An-Nisa · 69/176
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah An-Nisa
وَمَن يُطِعِ اللَّهَ وَالرَّسُولَ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الَّذِينَ أَنْعَمَ اللَّهُ عَلَيْهِم مِّنَ النَّبِيِّينَ وَالصِّدِّيقِينَ وَالشُّهَدَاءِ وَالصَّالِحِينَ ۚ وَحَسُنَ أُولَٰئِكَ رَفِيقًا ۝٦٩
Wa many-yuti`il laaha war Rasoola fa ulaaa`ika ma`al lazeena an`amal laahu `alaihim minan nabiyyeena wassiddeeqeena washshuhadaaa`i wassaaliheen; wa hasuna ulaaa`ika rafeeqaa
📖 Ni Yorùbá
Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise naa, awon wonyen maa wa (ninu Ogba Idera) pelu awon ti Allahu sedera fun ninu awon Anabi, awon olododo, awon t’o ku s’oju ogun esin ati awon eni rere. Awon wonyen si dara ni alabaarin

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 67-71 — Surah An-Nisa

67وَإِذًا لَّآتَيْنَاهُم مِّن لَّدُنَّا أَجْرًا عَظِيمًا
Nigba naa, dajudaju Awa iba fun won ni esan nla lati odo Wa
68وَلَهَدَيْنَاهُمْ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا
Ati pe dajudaju Awa iba to won si ona taara
69وَمَن يُطِعِ اللَّهَ وَالرَّسُولَ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الَّذِينَ أَنْعَمَ اللَّهُ عَلَيْهِم مِّنَ النَّبِيِّينَ وَالصِّدِّيقِينَ وَالشُّهَدَاءِ وَالصَّالِحِينَ ۚ وَحَسُنَ أُولَٰئِكَ رَفِيقًا
Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise naa, awon wonyen maa wa (ninu Ogba Idera) pelu awon ti Allahu sedera fun ninu awon Anabi, awon olododo, awon t’o ku s’oju ogun esin ati awon eni rere. Awon wonyen si dara ni alabaarin
70ذَٰلِكَ الْفَضْلُ مِنَ اللَّهِ ۚ وَكَفَىٰ بِاللَّهِ عَلِيمًا
Oore ajulo yen maa wa lati odo Allahu; Allahu si to ni Onimo
71يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا خُذُوا حِذْرَكُمْ فَانفِرُوا ثُبَاتٍ أَوِ انفِرُوا جَمِيعًا
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e mu ohun isora yin lowo, ki e si tu jade s’oju ogun esin nikoniko tabi ki e tu jade ni apapo
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
69Ẹsẹ

Itumọ — An-Nisa 69

Surah An-Nisa Ẹsẹ 69 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise…

Surah Ẹsẹ 69/176 — Surah An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah An-Nisa Gbọ, Surah An-Nisa Itumọ, Surah An-Nisa mp3, Surah An-Nisa pdf. Ẹsẹ 67–71. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers