Qaf · 12/45
Itumọ Aṣẹ ohun — Qaf
كَذَّبَتْ قَبْلَهُمْ قَوْمُ نُوحٍ وَأَصْحَابُ الرَّسِّ وَثَمُودُ ۝١٢
Kazzabat qablahum qawmu Noohinw wa Ashaabur Rassi wa Samood
📖 Ni Yorùbá
Awon eniyan (Anabi) Nuh, awon eniyan Rass ati awon (eniyan) Thamud pe ododo niro siwaju won
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 10-14 — Qaf

10وَالنَّخْلَ بَاسِقَاتٍ لَّهَا طَلْعٌ نَّضِيدٌ
(A tun mu) igi dabinu hu ga, ti awon eso ori re so jigbinni
11رِّزْقًا لِّلْعِبَادِ ۖ وَأَحْيَيْنَا بِهِ بَلْدَةً مَّيْتًا ۚ كَذَٰلِكَ الْخُرُوجُ
Arisiki ni fun awon eru (Allahu). A si n fi so oku ile di aye. Bayen ni ijade eda (lati inu saree yo se ri)
12كَذَّبَتْ قَبْلَهُمْ قَوْمُ نُوحٍ وَأَصْحَابُ الرَّسِّ وَثَمُودُ
Awon eniyan (Anabi) Nuh, awon eniyan Rass ati awon (eniyan) Thamud pe ododo niro siwaju won
13وَعَادٌ وَفِرْعَوْنُ وَإِخْوَانُ لُوطٍ
Ati awon ‘Ad, Fir‘aon ati awon omo iya (Anabi) Lut
14وَأَصْحَابُ الْأَيْكَةِ وَقَوْمُ تُبَّعٍ ۚ كُلٌّ كَذَّبَ الرُّسُلَ فَحَقَّ وَعِيدِ
ati awon ara ’Aekah ati awon ijo Tubba‘u; gbogbo won pe awon Ojise ni opuro. Nitori naa, ileri Mi si di eto (lori won)
QafAtokọ Kurani
45Ẹsẹ
MeccanRevelation
12Ẹsẹ

Itumọ — Qaf 12

Surah Qaf Ẹsẹ 12 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon eniyan (Anabi) Nuh, awon eniyan Rass ati awon (eniyan)…

Surah Ẹsẹ 12/45 — Qaf ق (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Qaf Gbọ, Qaf Itumọ, Qaf mp3, Qaf pdf. Ẹsẹ 10–14. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers