At-Tur · 26/49
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Tur
قَالُوا إِنَّا كُنَّا قَبْلُ فِي أَهْلِنَا مُشْفِقِينَ ۝٢٦
Qaalooo innaa kunnaa qablu feee ahlinaa mushfiqeen
📖 Ni Yorùbá
Won yoo so pe: "Dajudaju teletele awa je olupaya laaarin awon eniyan wa

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 24-28 — Surah At-Tur

24۞ وَيَطُوفُ عَلَيْهِمْ غِلْمَانٌ لَّهُمْ كَأَنَّهُمْ لُؤْلُؤٌ مَّكْنُونٌ
Awon omo-odo won yo si maa lo bo laaarin won. (Won) da bi aluuulu afipamo
25وَأَقْبَلَ بَعْضُهُمْ عَلَىٰ بَعْضٍ يَتَسَاءَلُونَ
Apa kan won yoo doju ko apa kan, won yo si maa beere oro lowo ara won
26قَالُوا إِنَّا كُنَّا قَبْلُ فِي أَهْلِنَا مُشْفِقِينَ
Won yoo so pe: "Dajudaju teletele awa je olupaya laaarin awon eniyan wa
27فَمَنَّ اللَّهُ عَلَيْنَا وَوَقَانَا عَذَابَ السَّمُومِ
Sugbon Allahu saanu wa. O si la wa nibi iya Ina
28إِنَّا كُنَّا مِن قَبْلُ نَدْعُوهُ ۖ إِنَّهُ هُوَ الْبَرُّ الرَّحِيمُ
Dajudaju awa maa n pe E teletele. Dajudaju Allahu, Oun ni Oloore, Asake-orun
At-TurAtokọ Kurani
49Ẹsẹ
MeccanRevelation
26Ẹsẹ

Itumọ — At-Tur 26

Surah At-Tur Ẹsẹ 26 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won yoo so pe: "Dajudaju teletele awa je olupaya laaarin…

Surah Ẹsẹ 26/49 — Surah At-Tur الطور (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Tur Gbọ, Surah At-Tur Itumọ, Surah At-Tur mp3, Surah At-Tur pdf. Ẹsẹ 24–28. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers