At-Tur · 47/49
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Tur
وَإِنَّ لِلَّذِينَ ظَلَمُوا عَذَابًا دُونَ ذَٰلِكَ وَلَٰكِنَّ أَكْثَرَهُمْ لَا يَعْلَمُونَ ٤٧
Transliteration
Wa inna lillazeena zalamoo `azaaban doona zalika wa laakinna aksarahum laa ya`lamoon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Ati pe dajudaju iya kan n be fun awon t’o sabosi yato si (iya orun) yen, sugbon opolopo won ni ko mo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 45-49 — Surah At-Tur
45فَذَرْهُمْ حَتَّىٰ يُلَاقُوا يَوْمَهُمُ الَّذِي فِيهِ يُصْعَقُونَ
Nitori naa, fi won sile titi won yoo fi ba ojo won ti won maa pa won sinu re pade
46يَوْمَ لَا يُغْنِي عَنْهُمْ كَيْدُهُمْ شَيْئًا وَلَا هُمْ يُنصَرُونَ
Ojo ti ete won ko nii fi kini kan ro won loro. A o si nii ran won lowo
47وَإِنَّ لِلَّذِينَ ظَلَمُوا عَذَابًا دُونَ ذَٰلِكَ وَلَٰكِنَّ أَكْثَرَهُمْ لَا يَعْلَمُونَ
Ati pe dajudaju iya kan n be fun awon t’o sabosi yato si (iya orun) yen, sugbon opolopo won ni ko mo
48وَاصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ فَإِنَّكَ بِأَعْيُنِنَا ۖ وَسَبِّحْ بِحَمْدِ رَبِّكَ حِينَ تَقُومُ
Se suuru fun idajo Oluwa Re, dajudaju iwo wa ni ojuto Wa. Ki o si se afomo pelu idupe fun Oluwa re nigba ti o ba n dide naro (fun irun kiki)
49وَمِنَ اللَّيْلِ فَسَبِّحْهُ وَإِدْبَارَ النُّجُومِ
Ati ni ale (nigba ti) awon irawo ba kuro nita tan, safomo fun Un
At-TurAtokọ Kurani
49Ẹsẹ
MeccanRevelation
47Ẹsẹ
Itumọ — At-Tur 47
Surah At-Tur Ẹsẹ 47 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe dajudaju iya kan n be fun awon t’o…Surah Ẹsẹ 47/49 — Surah At-Tur الطور (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Tur Gbọ, Surah At-Tur Itumọ, Surah At-Tur mp3, Surah At-Tur pdf. Ẹsẹ 45–49. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








