Al-Mulk · 26/30
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Mulk
قُلْ إِنَّمَا الْعِلْمُ عِندَ اللَّهِ وَإِنَّمَا أَنَا نَذِيرٌ مُّبِينٌ ۝٢٦
Qul innamal `ilmu `indallaahi wa innamaaa ana nazeerum mubeen
📖 Ni Yorùbá
So pe: "Odo Allahu nikan ni imo (nipa) re wa. Emi kan je olukilo ponnbele ni

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 24-28 — Al-Mulk

24قُلْ هُوَ الَّذِي ذَرَأَكُمْ فِي الْأَرْضِ وَإِلَيْهِ تُحْشَرُونَ
So pe: "Oun ni Eni ti O da yin si ori ile. Odo Re si ni won yoo ko yin jo si
25وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا الْوَعْدُ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
Won n wi pe: "Igba wo ni adehun yii yoo se ti e ba je olododo
26قُلْ إِنَّمَا الْعِلْمُ عِندَ اللَّهِ وَإِنَّمَا أَنَا نَذِيرٌ مُّبِينٌ
So pe: "Odo Allahu nikan ni imo (nipa) re wa. Emi kan je olukilo ponnbele ni
27فَلَمَّا رَأَوْهُ زُلْفَةً سِيئَتْ وُجُوهُ الَّذِينَ كَفَرُوا وَقِيلَ هَٰذَا الَّذِي كُنتُم بِهِ تَدَّعُونَ
Nigba ti won ba ri i t’o sunmo, oju awon t’o sai gbagbo yoo koro wa fun ibanuje. A o si so fun won pe: "Eyi ni ohun ti e n pe
28قُلْ أَرَأَيْتُمْ إِنْ أَهْلَكَنِيَ اللَّهُ وَمَن مَّعِيَ أَوْ رَحِمَنَا فَمَن يُجِيرُ الْكَافِرِينَ مِنْ عَذَابٍ أَلِيمٍ
So pe: " E so fun mi, ti Allahu ba pa emi ati awon t’o wa pelu mi re, tabi ti O ba ke wa (se e le di I lowo ni?) Nitori naa, ta ni o maa gba awon alaigbagbo la ninu iya eleta-elero
Al-MulkAtokọ Kurani
30Ẹsẹ
MeccanRevelation
26Ẹsẹ

Itumọ — Al-Mulk 26

Surah Al-Mulk Ẹsẹ 26 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : So pe: "Odo Allahu nikan ni imo (nipa) re wa.…

Surah Ẹsẹ 26/30 — Al-Mulk الملك (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Mulk Gbọ, Al-Mulk Itumọ, Al-Mulk mp3, Al-Mulk pdf. Ẹsẹ 24–28. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers