Al-Mulk · 25/30
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Mulk
وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا الْوَعْدُ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ ۝٢٥
Wa yaqooloona mataa haazal wa`du in kuntum saadiqeen
📖 Ni Yorùbá
Won n wi pe: "Igba wo ni adehun yii yoo se ti e ba je olododo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 23-27 — Surah Al-Mulk

23قُلْ هُوَ الَّذِي أَنشَأَكُمْ وَجَعَلَ لَكُمُ السَّمْعَ وَالْأَبْصَارَ وَالْأَفْئِدَةَ ۖ قَلِيلًا مَّا تَشْكُرُونَ
So pe: "Oun ni Eni ti O seda yin. O si se igboro, iriran ati awon okan fun yin. Ope ti e n da si kere pupo
24قُلْ هُوَ الَّذِي ذَرَأَكُمْ فِي الْأَرْضِ وَإِلَيْهِ تُحْشَرُونَ
So pe: "Oun ni Eni ti O da yin si ori ile. Odo Re si ni won yoo ko yin jo si
25وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا الْوَعْدُ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
Won n wi pe: "Igba wo ni adehun yii yoo se ti e ba je olododo
26قُلْ إِنَّمَا الْعِلْمُ عِندَ اللَّهِ وَإِنَّمَا أَنَا نَذِيرٌ مُّبِينٌ
So pe: "Odo Allahu nikan ni imo (nipa) re wa. Emi kan je olukilo ponnbele ni
27فَلَمَّا رَأَوْهُ زُلْفَةً سِيئَتْ وُجُوهُ الَّذِينَ كَفَرُوا وَقِيلَ هَٰذَا الَّذِي كُنتُم بِهِ تَدَّعُونَ
Nigba ti won ba ri i t’o sunmo, oju awon t’o sai gbagbo yoo koro wa fun ibanuje. A o si so fun won pe: "Eyi ni ohun ti e n pe
Al-MulkAtokọ Kurani
30Ẹsẹ
MeccanRevelation
25Ẹsẹ

Itumọ — Al-Mulk 25

Surah Al-Mulk Ẹsẹ 25 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won n wi pe: "Igba wo ni adehun yii yoo…

Surah Ẹsẹ 25/30 — Surah Al-Mulk الملك (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Mulk Gbọ, Surah Al-Mulk Itumọ, Surah Al-Mulk mp3, Surah Al-Mulk pdf. Ẹsẹ 23–27. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers