Al-Qalam · 27/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
بَلْ نَحْنُ مَحْرُومُونَ ۝٢٧
Bal nahnu mahroomoon
📖 Ni Yorùbá
Rara o, won se ikore oko leewo fun wa ni

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 25-29 — Surah Al-Qalam

25وَغَدَوْا عَلَىٰ حَرْدٍ قَادِرِينَ
Won ji lo lori ero-okan kan (pe) awon lagbara
26فَلَمَّا رَأَوْهَا قَالُوا إِنَّا لَضَالُّونَ
Nigba ti won ri i, won wi pe: "Dajudaju awa ti sina
27بَلْ نَحْنُ مَحْرُومُونَ
Rara o, won se ikore oko leewo fun wa ni
28قَالَ أَوْسَطُهُمْ أَلَمْ أَقُل لَّكُمْ لَوْلَا تُسَبِّحُونَ
Eni t’o duro deede julo ninu won so pe: "Se emi ko so fun yin pe eyin ko se safomo fun Allahu (pe "a maa kore oko wa, ’in sa ’Allahu)
29قَالُوا سُبْحَانَ رَبِّنَا إِنَّا كُنَّا ظَالِمِينَ
Won wi pe: "Mimo ni fun Oluwa wa, dajudaju awa je alabosi
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
27Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 27

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 27 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Rara o, won se ikore oko leewo fun wa ni

Surah Ẹsẹ 27/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 25–29. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers