Al-Qalam · 28/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
قَالَ أَوْسَطُهُمْ أَلَمْ أَقُل لَّكُمْ لَوْلَا تُسَبِّحُونَ ۝٢٨
Qaala awsatuhum alam aqul lakum law laa tusabbihoon
📖 Ni Yorùbá
Eni t’o duro deede julo ninu won so pe: "Se emi ko so fun yin pe eyin ko se safomo fun Allahu (pe "a maa kore oko wa, ’in sa ’Allahu)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 26-30 — Surah Al-Qalam

26فَلَمَّا رَأَوْهَا قَالُوا إِنَّا لَضَالُّونَ
Nigba ti won ri i, won wi pe: "Dajudaju awa ti sina
27بَلْ نَحْنُ مَحْرُومُونَ
Rara o, won se ikore oko leewo fun wa ni
28قَالَ أَوْسَطُهُمْ أَلَمْ أَقُل لَّكُمْ لَوْلَا تُسَبِّحُونَ
Eni t’o duro deede julo ninu won so pe: "Se emi ko so fun yin pe eyin ko se safomo fun Allahu (pe "a maa kore oko wa, ’in sa ’Allahu)
29قَالُوا سُبْحَانَ رَبِّنَا إِنَّا كُنَّا ظَالِمِينَ
Won wi pe: "Mimo ni fun Oluwa wa, dajudaju awa je alabosi
30فَأَقْبَلَ بَعْضُهُمْ عَلَىٰ بَعْضٍ يَتَلَاوَمُونَ
Apa kan won koju si apa kan; won si n dara won lebi
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
28Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 28

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 28 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eni t’o duro deede julo ninu won so pe: "Se…

Surah Ẹsẹ 28/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 26–30. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers