Al-Qalam · 26/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
فَلَمَّا رَأَوْهَا قَالُوا إِنَّا لَضَالُّونَ ۝٢٦
Falammaa ra awhaa qaalooo innaa ladaaalloon
📖 Ni Yorùbá
Nigba ti won ri i, won wi pe: "Dajudaju awa ti sina

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 24-28 — Surah Al-Qalam

24أَن لَّا يَدْخُلَنَّهَا الْيَوْمَ عَلَيْكُم مِّسْكِينٌ
pe ni oni mekunnu kan ko gbodo wonu re wa ba yin
25وَغَدَوْا عَلَىٰ حَرْدٍ قَادِرِينَ
Won ji lo lori ero-okan kan (pe) awon lagbara
26فَلَمَّا رَأَوْهَا قَالُوا إِنَّا لَضَالُّونَ
Nigba ti won ri i, won wi pe: "Dajudaju awa ti sina
27بَلْ نَحْنُ مَحْرُومُونَ
Rara o, won se ikore oko leewo fun wa ni
28قَالَ أَوْسَطُهُمْ أَلَمْ أَقُل لَّكُمْ لَوْلَا تُسَبِّحُونَ
Eni t’o duro deede julo ninu won so pe: "Se emi ko so fun yin pe eyin ko se safomo fun Allahu (pe "a maa kore oko wa, ’in sa ’Allahu)
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
26Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 26

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 26 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nigba ti won ri i, won wi pe: "Dajudaju awa…

Surah Ẹsẹ 26/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 24–28. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers