Al-Anbiya · 22/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Anbiya
لَوْ كَانَ فِيهِمَا آلِهَةٌ إِلَّا اللَّهُ لَفَسَدَتَا ۚ فَسُبْحَانَ اللَّهِ رَبِّ الْعَرْشِ عَمَّا يَصِفُونَ ۝٢٢
Law kaana feehimaaa aalihatun illal laahu lafasadataa; fa-Subhaanal laahi Rabbil `Arshi `ammaa yasifoon
📖 Ni Yorùbá
Ti o ba je pe awon olohun kan wa ninu sanmo ati ile leyin Allahu, sanmo ati ile iba ti baje. Mimo ni fun Allahu, Oluwa Ite-ola, tayo ohun ti won n fi royin (Re)
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 20-24 — Al-Anbiya

20يُسَبِّحُونَ اللَّيْلَ وَالنَّهَارَ لَا يَفْتُرُونَ
Won n safomo ni oru ati ni osan; ko si re won
21أَمِ اتَّخَذُوا آلِهَةً مِّنَ الْأَرْضِ هُمْ يُنشِرُونَ
Tabi won ni awon olohun kan ti won mu jade lati ara ile, ti won n ji oku dide ni
22لَوْ كَانَ فِيهِمَا آلِهَةٌ إِلَّا اللَّهُ لَفَسَدَتَا ۚ فَسُبْحَانَ اللَّهِ رَبِّ الْعَرْشِ عَمَّا يَصِفُونَ
Ti o ba je pe awon olohun kan wa ninu sanmo ati ile leyin Allahu, sanmo ati ile iba ti baje. Mimo ni fun Allahu, Oluwa Ite-ola, tayo ohun ti won n fi royin (Re)
23لَا يُسْأَلُ عَمَّا يَفْعَلُ وَهُمْ يُسْأَلُونَ
Won ko nii bi (Allahu) ni ibeere nipa nnkan ti O n se. Awon ni won maa bi ni ibeere (nipa ise owo won)
24أَمِ اتَّخَذُوا مِن دُونِهِ آلِهَةً ۖ قُلْ هَاتُوا بُرْهَانَكُمْ ۖ هَٰذَا ذِكْرُ مَن مَّعِيَ وَذِكْرُ مَن قَبْلِي ۗ بَلْ أَكْثَرُهُمْ لَا يَعْلَمُونَ الْحَقَّ ۖ فَهُم مُّعْرِضُونَ
Tabi won so awon kan di olohun leyin Allahu ni? So pe: “E mu eri oro yin wa.” (Al-Ƙur’an) yii ni iranti nipa awon t’o wa pelu mi ati iranti nipa awon t’o siwaju mi. Sugbon opolopo won ko mo ododo; won si n gbunri kuro nibe
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
22Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 22

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 22 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti o ba je pe awon olohun kan wa ninu…

Surah Ẹsẹ 22/112 — Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Anbiya Gbọ, Al-Anbiya Itumọ, Al-Anbiya mp3, Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 20–24. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers