Ar-Rahman · 14/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
خَلَقَ الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ ۝١٤
Khalaqal insaana min salsaalin kalfakhkhaari
📖 Ni Yorùbá
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 12-16 — Surah Ar-Rahman

12وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
13فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
14خَلَقَ الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
15وَخَلَقَ الْجَانَّ مِن مَّارِجٍ مِّن نَّارٍ
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
16فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
14Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 14

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 14 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun…

Surah Ẹsẹ 14/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 12–16. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers