Ar-Rahman · 13/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ ۝١٣
Fabi ayyi aalaaa`i Rabbikumaa tukazzibaan
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 11-15 — Surah Ar-Rahman

11فِيهَا فَاكِهَةٌ وَالنَّخْلُ ذَاتُ الْأَكْمَامِ
Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)
12وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
13فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
14خَلَقَ الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
15وَخَلَقَ الْجَانَّ مِن مَّارِجٍ مِّن نَّارٍ
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
13Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 13

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 13 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati…

Surah Ẹsẹ 13/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 11–15. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers