Ar-Rahman · 18/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ ۝١٨
Fabi ayyi aalaaa`i Rabbikumaa tukazzibaan
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 16-20 — Surah Ar-Rahman

16فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
17رَبُّ الْمَشْرِقَيْنِ وَرَبُّ الْمَغْرِبَيْنِ
Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji
18فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
19مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ يَلْتَقِيَانِ
(Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
20بَيْنَهُمَا بَرْزَخٌ لَّا يَبْغِيَانِ
Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko si le tayo enu-ala (re laaarin ara won)
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
18Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 18

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 18 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati…

Surah Ẹsẹ 18/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 16–20. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers