Al-Qalam · 19/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
فَطَافَ عَلَيْهَا طَائِفٌ مِّن رَّبِّكَ وَهُمْ نَائِمُونَ ۝١٩
Fataafa `alaihaa taaa`i fum mir rabbika wa hum naaa`imoon
📖 Ni Yorùbá
Adanwo t’o n yi nnkan po lati odo Oluwa re si yi ogba naa po, nigba ti won sun lo

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 17-21 — Surah Al-Qalam

17إِنَّا بَلَوْنَاهُمْ كَمَا بَلَوْنَا أَصْحَابَ الْجَنَّةِ إِذْ أَقْسَمُوا لَيَصْرِمُنَّهَا مُصْبِحِينَ
Dajudaju Awa dan won wo gege bi A se dan awon ologba wo nigba ti won bura pe dajudaju awon yoo ka gbogbo eso ogba naa ni owuro kutukutu
18وَلَا يَسْتَثْنُونَ
Won ko si se ayafi pe "ti Allahu ba fe
19فَطَافَ عَلَيْهَا طَائِفٌ مِّن رَّبِّكَ وَهُمْ نَائِمُونَ
Adanwo t’o n yi nnkan po lati odo Oluwa re si yi ogba naa po, nigba ti won sun lo
20فَأَصْبَحَتْ كَالصَّرِيمِ
O si da bi oko agedanu (ti won ti resun)
21فَتَنَادَوْا مُصْبِحِينَ
Won n pera won ni owuro kutukutu
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
19Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 19

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 19 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Adanwo t’o n yi nnkan po lati odo Oluwa re…

Surah Ẹsẹ 19/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 17–21. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers