Al-Qalam · 18/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
وَلَا يَسْتَثْنُونَ ۝١٨
Wa laa yastasnoon
📖 Ni Yorùbá
Won ko si se ayafi pe "ti Allahu ba fe

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 16-20 — Surah Al-Qalam

16سَنَسِمُهُ عَلَى الْخُرْطُومِ
A maa fi ami si i ni gongori imu
17إِنَّا بَلَوْنَاهُمْ كَمَا بَلَوْنَا أَصْحَابَ الْجَنَّةِ إِذْ أَقْسَمُوا لَيَصْرِمُنَّهَا مُصْبِحِينَ
Dajudaju Awa dan won wo gege bi A se dan awon ologba wo nigba ti won bura pe dajudaju awon yoo ka gbogbo eso ogba naa ni owuro kutukutu
18وَلَا يَسْتَثْنُونَ
Won ko si se ayafi pe "ti Allahu ba fe
19فَطَافَ عَلَيْهَا طَائِفٌ مِّن رَّبِّكَ وَهُمْ نَائِمُونَ
Adanwo t’o n yi nnkan po lati odo Oluwa re si yi ogba naa po, nigba ti won sun lo
20فَأَصْبَحَتْ كَالصَّرِيمِ
O si da bi oko agedanu (ti won ti resun)
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
18Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 18

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 18 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won ko si se ayafi pe "ti Allahu ba fe

Surah Ẹsẹ 18/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 16–20. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers