Al-Qalam · 36/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
مَا لَكُمْ كَيْفَ تَحْكُمُونَ ۝٣٦
Maa lakum kaifa tahhkumoon
📖 Ni Yorùbá
Ki l’o n se yin ti e fi n dajo bayii na

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 34-38 — Surah Al-Qalam

34إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّاتِ النَّعِيمِ
Dajudaju awon Ogba Idera wa fun awon oluberu lodo Oluwa won
35أَفَنَجْعَلُ الْمُسْلِمِينَ كَالْمُجْرِمِينَ
Se A maa se awon musulumi bi (A se maa se) awon elese bi
36مَا لَكُمْ كَيْفَ تَحْكُمُونَ
Ki l’o n se yin ti e fi n dajo bayii na
37أَمْ لَكُمْ كِتَابٌ فِيهِ تَدْرُسُونَ
Tabi tira kan wa fun yin ti e n kekoo ninu re
38إِنَّ لَكُمْ فِيهِ لَمَا تَخَيَّرُونَ
pe dajudaju eyin le ni ohun ti e ba n sa lesa ninu idajo
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
36Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 36

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 36 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ki l’o n se yin ti e fi n dajo…

Surah Ẹsẹ 36/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 34–38. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers