Al-Qalam · 39/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
أَمْ لَكُمْ أَيْمَانٌ عَلَيْنَا بَالِغَةٌ إِلَىٰ يَوْمِ الْقِيَامَةِ ۙ إِنَّ لَكُمْ لَمَا تَحْكُمُونَ ۝٣٩
Am lakum aymaanun `alainaa baalighatun ilaa yawmil qiyaamati inna lakum lamaa tahkumoon
📖 Ni Yorùbá
Nje e ni awon adehun kan lodo wa ti o maa wa titi di Ojo Ajinde pe: "Dajudaju tiyin ni idajo ti e ba ti mu wa

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 37-41 — Surah Al-Qalam

37أَمْ لَكُمْ كِتَابٌ فِيهِ تَدْرُسُونَ
Tabi tira kan wa fun yin ti e n kekoo ninu re
38إِنَّ لَكُمْ فِيهِ لَمَا تَخَيَّرُونَ
pe dajudaju eyin le ni ohun ti e ba n sa lesa ninu idajo
39أَمْ لَكُمْ أَيْمَانٌ عَلَيْنَا بَالِغَةٌ إِلَىٰ يَوْمِ الْقِيَامَةِ ۙ إِنَّ لَكُمْ لَمَا تَحْكُمُونَ
Nje e ni awon adehun kan lodo wa ti o maa wa titi di Ojo Ajinde pe: "Dajudaju tiyin ni idajo ti e ba ti mu wa
40سَلْهُمْ أَيُّهُم بِذَٰلِكَ زَعِيمٌ
Bi won leere wo pe ewo ninu won l’o le fowo iyen soya
41أَمْ لَهُمْ شُرَكَاءُ فَلْيَأْتُوا بِشُرَكَائِهِمْ إِن كَانُوا صَادِقِينَ
Tabi won ni awon orisa kan? Ki won mu awon orisa won wa nigba naa ti won ba je olododo
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
39Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 39

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 39 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nje e ni awon adehun kan lodo wa ti o…

Surah Ẹsẹ 39/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 37–41. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers