Al-Qalam · 7/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعْلَمُ بِمَن ضَلَّ عَن سَبِيلِهِ وَهُوَ أَعْلَمُ بِالْمُهْتَدِينَ ۝٧
Innaa Rabbaka Huwa a`lamu biman dalla `an sabeelihee wa Huwa a`lamu bilmuhtadeen
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju Oluwa re, O nimo julo nipa eni t’o sina kuro loju ona Re. O si nimo julo nipa awon olumona

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 5-9 — Surah Al-Qalam

5فَسَتُبْصِرُ وَيُبْصِرُونَ
Laipe iwo yoo ri i, awon naa yo si ri i
6بِأَييِّكُمُ الْمَفْتُونُ
ewo ninu yin ni were
7إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعْلَمُ بِمَن ضَلَّ عَن سَبِيلِهِ وَهُوَ أَعْلَمُ بِالْمُهْتَدِينَ
Dajudaju Oluwa re, O nimo julo nipa eni t’o sina kuro loju ona Re. O si nimo julo nipa awon olumona
8فَلَا تُطِعِ الْمُكَذِّبِينَ
Nitori naa, ma se tele awon olupe-ododo-niro
9وَدُّوا لَوْ تُدْهِنُ فَيُدْهِنُونَ
Ati pe won fe ki o dewo, ki awon naa si dewo
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
7Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 7

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 7 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju Oluwa re, O nimo julo nipa eni t’o sina…

Surah Ẹsẹ 7/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 5–9. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers