Al-Haqqah · 5/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Haqqah
فَأَمَّا ثَمُودُ فَأُهْلِكُوا بِالطَّاغِيَةِ ۝٥
Fa-ammaa Samoodu fauhlikoo bittaaghiyah
📖 Ni Yorùbá
Ni ti ijo Thamud, won fi igbe t’o tayo enu-ala pa won re
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 3-7 — Al-Haqqah

3وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْحَاقَّةُ
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Isele Ododo
4كَذَّبَتْ ثَمُودُ وَعَادٌ بِالْقَارِعَةِ
Awon ijo Thamud ati ijo ‘Ad pe Ipaya niro
5فَأَمَّا ثَمُودُ فَأُهْلِكُوا بِالطَّاغِيَةِ
Ni ti ijo Thamud, won fi igbe t’o tayo enu-ala pa won re
6وَأَمَّا عَادٌ فَأُهْلِكُوا بِرِيحٍ صَرْصَرٍ عَاتِيَةٍ
Ni ti ijo ‘Ad, won fi ategun lile t’o tayo enu-ala pa won re
7سَخَّرَهَا عَلَيْهِمْ سَبْعَ لَيَالٍ وَثَمَانِيَةَ أَيَّامٍ حُسُومًا فَتَرَى الْقَوْمَ فِيهَا صَرْعَىٰ كَأَنَّهُمْ أَعْجَازُ نَخْلٍ خَاوِيَةٍ
O de e si won fun oru meje ati osan mejo lai dawo duro. O si maa ri ijo naa ti won ti ku sinu re bi eni pe kukute igi dabinu t’o ti luho ninu ni won
Al-HaqqahAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
5Ẹsẹ

Itumọ — Al-Haqqah 5

Surah Al-Haqqah Ẹsẹ 5 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ni ti ijo Thamud, won fi igbe t’o tayo enu-ala…

Surah Ẹsẹ 5/52 — Al-Haqqah الحاقة (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Haqqah Gbọ, Al-Haqqah Itumọ, Al-Haqqah mp3, Al-Haqqah pdf. Ẹsẹ 3–7. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers