Al-A'raf · 59/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-A'raf
لَقَدْ أَرْسَلْنَا نُوحًا إِلَىٰ قَوْمِهِ فَقَالَ يَا قَوْمِ اعْبُدُوا اللَّهَ مَا لَكُم مِّنْ إِلَٰهٍ غَيْرُهُ إِنِّي أَخَافُ عَلَيْكُمْ عَذَابَ يَوْمٍ عَظِيمٍ ۝٥٩
Laqad arsalnaa noohan ilaa qawmihee faqaala yaa qawmi` budul laaha maa lakum min ilaahin ghairuhoo inneee akhaafu `alaikum `azaaba Yawmin `Azeem
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju A ran (Anabi) Nuh nise si ijo re. O si so pe: "Eyin ijo mi, e josin fun Allahu. E o ni olohun miiran leyin Re. Dajudaju mo n beru iya Ojo Nla fun yin

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 57-61 — Surah Al-A'raf

57وَهُوَ الَّذِي يُرْسِلُ الرِّيَاحَ بُشْرًا بَيْنَ يَدَيْ رَحْمَتِهِ ۖ حَتَّىٰ إِذَا أَقَلَّتْ سَحَابًا ثِقَالًا سُقْنَاهُ لِبَلَدٍ مَّيِّتٍ فَأَنزَلْنَا بِهِ الْمَاءَ فَأَخْرَجْنَا بِهِ مِن كُلِّ الثَّمَرَاتِ ۚ كَذَٰلِكَ نُخْرِجُ الْمَوْتَىٰ لَعَلَّكُمْ تَذَكَّرُونَ
Oun ni Eni t’O n ran ategun (t’o je) iro idunnu siwaju aanu Re, titi (ategun naa) yoo fi gbe esujo t’o wuwo, ti A si maa wo o lo si oku ile. Nigba naa, A maa fi so omi kale. A si maa mu orisirisi eso jade. Bayen ni A o se mu awon oku jade nitori ki e le lo iranti
58وَالْبَلَدُ الطَّيِّبُ يَخْرُجُ نَبَاتُهُ بِإِذْنِ رَبِّهِ ۖ وَالَّذِي خَبُثَ لَا يَخْرُجُ إِلَّا نَكِدًا ۚ كَذَٰلِكَ نُصَرِّفُ الْآيَاتِ لِقَوْمٍ يَشْكُرُونَ
(Ile) ilu t’o dara, awon irugbin re yoo jade pelu ase Oluwa re. Eyi ti ko si dara, (irugbin re) ko nii jade afi (die) pelu inira. Bayen ni A se n mu awon ayah wa loniran-anran ona fun ijo t’o n dupe
59لَقَدْ أَرْسَلْنَا نُوحًا إِلَىٰ قَوْمِهِ فَقَالَ يَا قَوْمِ اعْبُدُوا اللَّهَ مَا لَكُم مِّنْ إِلَٰهٍ غَيْرُهُ إِنِّي أَخَافُ عَلَيْكُمْ عَذَابَ يَوْمٍ عَظِيمٍ
Dajudaju A ran (Anabi) Nuh nise si ijo re. O si so pe: "Eyin ijo mi, e josin fun Allahu. E o ni olohun miiran leyin Re. Dajudaju mo n beru iya Ojo Nla fun yin
60قَالَ الْمَلَأُ مِن قَوْمِهِ إِنَّا لَنَرَاكَ فِي ضَلَالٍ مُّبِينٍ
Awon agbaagba ninu ijo re wi pe: "Dajudaju awa n ri o pe o wa ninu isina ponnbele
61قَالَ يَا قَوْمِ لَيْسَ بِي ضَلَالَةٌ وَلَٰكِنِّي رَسُولٌ مِّن رَّبِّ الْعَالَمِينَ
O so pe: "Eyin ijo mi, ko si isina kan lodo mi, sugbon dajudaju emi ni Ojise kan lati odo Oluwa gbogbo eda
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
59Ẹsẹ

Itumọ — Al-A'raf 59

Surah Al-A'raf Ẹsẹ 59 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju A ran (Anabi) Nuh nise si ijo re. O…

Surah Ẹsẹ 59/206 — Surah Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-A'raf Gbọ, Surah Al-A'raf Itumọ, Surah Al-A'raf mp3, Surah Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 57–61. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers