Al-Ma'arij · 37/44
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Ma'arij
عَنِ الْيَمِينِ وَعَنِ الشِّمَالِ عِزِينَ ۝٣٧
Anil yameeni wa `anish shimaali `izeen
📖 Ni Yorùbá
ti won si jokoo ni isori isori si owo otun ati owo osi (re)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 35-39 — Surah Al-Ma'arij

35أُولَٰئِكَ فِي جَنَّاتٍ مُّكْرَمُونَ
Awon wonyen ni alapon-onle ninu awon Ogba Idera
36فَمَالِ الَّذِينَ كَفَرُوا قِبَلَكَ مُهْطِعِينَ
Ki lo mu awon ti ko gbagbo ti ara won ko bale niwaju re
37عَنِ الْيَمِينِ وَعَنِ الشِّمَالِ عِزِينَ
ti won si jokoo ni isori isori si owo otun ati owo osi (re)
38أَيَطْمَعُ كُلُّ امْرِئٍ مِّنْهُمْ أَن يُدْخَلَ جَنَّةَ نَعِيمٍ
Se eni kookan ninu won n jerankan pe A oo mu oun wo inu Ogba Idera ni
39كَلَّا ۖ إِنَّا خَلَقْنَاهُم مِّمَّا يَعْلَمُونَ
Rara o! Dajudaju Awa seda won lati inu ohun ti won mo
Al-Ma'arijAtokọ Kurani
44Ẹsẹ
MeccanRevelation
37Ẹsẹ

Itumọ — Al-Ma'arij 37

Surah Al-Ma'arij Ẹsẹ 37 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : ti won si jokoo ni isori isori si owo otun…

Surah Ẹsẹ 37/44 — Surah Al-Ma'arij المعارج (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Ma'arij Gbọ, Surah Al-Ma'arij Itumọ, Surah Al-Ma'arij mp3, Surah Al-Ma'arij pdf. Ẹsẹ 35–39. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers