Al-Ma'arij · 36/44
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Ma'arij
فَمَالِ الَّذِينَ كَفَرُوا قِبَلَكَ مُهْطِعِينَ ۝٣٦
Famaa lil lazeena kafaroo qibalaka muhti`een
📖 Ni Yorùbá
Ki lo mu awon ti ko gbagbo ti ara won ko bale niwaju re

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 34-38 — Surah Al-Ma'arij

34وَالَّذِينَ هُمْ عَلَىٰ صَلَاتِهِمْ يُحَافِظُونَ
ati awon t’o n so awon irun won
35أُولَٰئِكَ فِي جَنَّاتٍ مُّكْرَمُونَ
Awon wonyen ni alapon-onle ninu awon Ogba Idera
36فَمَالِ الَّذِينَ كَفَرُوا قِبَلَكَ مُهْطِعِينَ
Ki lo mu awon ti ko gbagbo ti ara won ko bale niwaju re
37عَنِ الْيَمِينِ وَعَنِ الشِّمَالِ عِزِينَ
ti won si jokoo ni isori isori si owo otun ati owo osi (re)
38أَيَطْمَعُ كُلُّ امْرِئٍ مِّنْهُمْ أَن يُدْخَلَ جَنَّةَ نَعِيمٍ
Se eni kookan ninu won n jerankan pe A oo mu oun wo inu Ogba Idera ni
Al-Ma'arijAtokọ Kurani
44Ẹsẹ
MeccanRevelation
36Ẹsẹ

Itumọ — Al-Ma'arij 36

Surah Al-Ma'arij Ẹsẹ 36 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ki lo mu awon ti ko gbagbo ti ara won…

Surah Ẹsẹ 36/44 — Surah Al-Ma'arij المعارج (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Ma'arij Gbọ, Surah Al-Ma'arij Itumọ, Surah Al-Ma'arij mp3, Surah Al-Ma'arij pdf. Ẹsẹ 34–38. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers