Al-Mutaffifin · 29/36
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Mutaffifin
إِنَّ الَّذِينَ أَجْرَمُوا كَانُوا مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا يَضْحَكُونَ ٢٩
Transliteration
Innal lazeena ajramoo kaanoo minal lazeena aamanoo yadhakoon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon t’o dese, won maa n fi awon t’o gbagbo ni ododo rerin-in
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 27-31 — Al-Mutaffifin
27وَمِزَاجُهُ مِن تَسْنِيمٍ
Tesnim ni won yoo maa popo (mo oti naa)
28عَيْنًا يَشْرَبُ بِهَا الْمُقَرَّبُونَ
(Tesnim ni) omi iseleru kan, ti awon olusunmo (Allahu) yoo maa mu
29إِنَّ الَّذِينَ أَجْرَمُوا كَانُوا مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا يَضْحَكُونَ
Dajudaju awon t’o dese, won maa n fi awon t’o gbagbo ni ododo rerin-in
30وَإِذَا مَرُّوا بِهِمْ يَتَغَامَزُونَ
Nigba ti won ba gba egbe won koja, (awon adese) yoo maa seju sira won ni ti yeye
31وَإِذَا انقَلَبُوا إِلَىٰ أَهْلِهِمُ انقَلَبُوا فَكِهِينَ
Nigba ti won ba si pada si odo awon eniyan won, won a pada ti won yoo maa se faari
Al-MutaffifinAtokọ Kurani
36Ẹsẹ
MeccanRevelation
29Ẹsẹ
Itumọ — Al-Mutaffifin 29
Surah Al-Mutaffifin Ẹsẹ 29 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon t’o dese, won maa n fi awon t’o…Surah Ẹsẹ 29/36 — Al-Mutaffifin المطففين (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Mutaffifin Gbọ, Al-Mutaffifin Itumọ, Al-Mutaffifin mp3, Al-Mutaffifin pdf. Ẹsẹ 27–31. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








