As-Sajdah · 4/30
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah As-Sajdah
اللَّهُ الَّذِي خَلَقَ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضَ وَمَا بَيْنَهُمَا فِي سِتَّةِ أَيَّامٍ ثُمَّ اسْتَوَىٰ عَلَى الْعَرْشِ ۖ مَا لَكُم مِّن دُونِهِ مِن وَلِيٍّ وَلَا شَفِيعٍ ۚ أَفَلَا تَتَذَكَّرُونَ ٤
Transliteration
Allaahul lazee khalaqas samaawaati wal arda wa maa bainahumaa fee sittati ayyaam;Thummas tawaa `alal `arsh; maa lakum min doonihee minw-wwaliyyinw-wala shafee`; afala tatazakkaroon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Allahu ni Eni ti O seda awon sanmo, ile ati nnkan t’o wa laaarin mejeeji laaarin ojo mefa. Leyin naa, O gunwa sori Ite-ola. Ko si alaabo ati olusipe kan fun yin leyin Re. Se e o nii lo iranti ni
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 2-6 — Surah As-Sajdah
2تَنزِيلُ الْكِتَابِ لَا رَيْبَ فِيهِ مِن رَّبِّ الْعَالَمِينَ
Isokale Tira naa, ko si iyemeji ninu re (pe o wa) lati odo Oluwa gbogbo eda
3أَمْ يَقُولُونَ افْتَرَاهُ ۚ بَلْ هُوَ الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ لِتُنذِرَ قَوْمًا مَّا أَتَاهُم مِّن نَّذِيرٍ مِّن قَبْلِكَ لَعَلَّهُمْ يَهْتَدُونَ
Tabi won n wi pe: “O da adapa iro re ni.” Rara o! Ododo ni lati odo Oluwa re nitori ki o le fi sekilo fun awon eniyan kan, ti olukilo kan ko wa ba won ri siwaju re, nitori ki won le mona
4اللَّهُ الَّذِي خَلَقَ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضَ وَمَا بَيْنَهُمَا فِي سِتَّةِ أَيَّامٍ ثُمَّ اسْتَوَىٰ عَلَى الْعَرْشِ ۖ مَا لَكُم مِّن دُونِهِ مِن وَلِيٍّ وَلَا شَفِيعٍ ۚ أَفَلَا تَتَذَكَّرُونَ
Allahu ni Eni ti O seda awon sanmo, ile ati nnkan t’o wa laaarin mejeeji laaarin ojo mefa. Leyin naa, O gunwa sori Ite-ola. Ko si alaabo ati olusipe kan fun yin leyin Re. Se e o nii lo iranti ni
5يُدَبِّرُ الْأَمْرَ مِنَ السَّمَاءِ إِلَى الْأَرْضِ ثُمَّ يَعْرُجُ إِلَيْهِ فِي يَوْمٍ كَانَ مِقْدَارُهُ أَلْفَ سَنَةٍ مِّمَّا تَعُدُّونَ
O n seto oro (eda) lati sanmo wa sori ile. Leyin naa, (abo oro eda) yoo gunke to O lo laaarin ojo kan ti odiwon re to egberun odun ninu onka ti e n ka
6ذَٰلِكَ عَالِمُ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ الْعَزِيزُ الرَّحِيمُ
Iyen ni Onimo-ikoko ati gbangba, Alagbara, Asake-orun
As-SajdahAtokọ Kurani
30Ẹsẹ
MeccanRevelation
4Ẹsẹ
Itumọ — As-Sajdah 4
Surah As-Sajdah Ẹsẹ 4 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Allahu ni Eni ti O seda awon sanmo, ile ati…Surah Ẹsẹ 4/30 — Surah As-Sajdah السجدة (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah As-Sajdah Gbọ, Surah As-Sajdah Itumọ, Surah As-Sajdah mp3, Surah As-Sajdah pdf. Ẹsẹ 2–6. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








