Muhammad · 24/38
Itumọ Aṣẹ ohun — Muhammad
أَفَلَا يَتَدَبَّرُونَ الْقُرْآنَ أَمْ عَلَىٰ قُلُوبٍ أَقْفَالُهَا ٢٤
Transliteration
Afalaa yatadabbaroonal Qur-aana am `alaa quloobin aqfaaluhaa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Se won ko nii ronu nipa al-Ƙur’an ni tabi awon agadagodo ti wa lori okan won ni
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 22-26 — Muhammad
22فَهَلْ عَسَيْتُمْ إِن تَوَلَّيْتُمْ أَن تُفْسِدُوا فِي الْأَرْضِ وَتُقَطِّعُوا أَرْحَامَكُمْ
Nje ko sunmo ti eyin (alaisan okan wonyi) ba de’po ase, pe e o nii sebaje lori ile ati pe e o nii ja okun-ibi yin
23أُولَٰئِكَ الَّذِينَ لَعَنَهُمُ اللَّهُ فَأَصَمَّهُمْ وَأَعْمَىٰ أَبْصَارَهُمْ
Awon wonyen ni awon ti Allahu ti sebi le. Nitori naa, O di won leti pa. O si fo iriran won
24أَفَلَا يَتَدَبَّرُونَ الْقُرْآنَ أَمْ عَلَىٰ قُلُوبٍ أَقْفَالُهَا
Se won ko nii ronu nipa al-Ƙur’an ni tabi awon agadagodo ti wa lori okan won ni
25إِنَّ الَّذِينَ ارْتَدُّوا عَلَىٰ أَدْبَارِهِم مِّن بَعْدِ مَا تَبَيَّنَ لَهُمُ الْهُدَى ۙ الشَّيْطَانُ سَوَّلَ لَهُمْ وَأَمْلَىٰ لَهُمْ
Dajudaju awon t’o peyin da (si ’Islam) leyin ti imona ti foju han si won, Esu lo se isina ni oso fun won. O si fun won ni ireti asan nipa emi gigun
26ذَٰلِكَ بِأَنَّهُمْ قَالُوا لِلَّذِينَ كَرِهُوا مَا نَزَّلَ اللَّهُ سَنُطِيعُكُمْ فِي بَعْضِ الْأَمْرِ ۖ وَاللَّهُ يَعْلَمُ إِسْرَارَهُمْ
Iyen nitori pe (awon alaisan okan) n so fun awon t’o korira ohun ti Allahu sokale pe: "Awa yoo tele yin ninu apa kan oro naa." Allahu si mo asiri won
MuhammadAtokọ Kurani
38Ẹsẹ
MedinanRevelation
24Ẹsẹ
Itumọ — Muhammad 24
Surah Muhammad Ẹsẹ 24 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Se won ko nii ronu nipa al-Ƙur’an ni tabi awon…Surah Ẹsẹ 24/38 — Muhammad محمد (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Muhammad Gbọ, Muhammad Itumọ, Muhammad mp3, Muhammad pdf. Ẹsẹ 22–26. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








