Al-Fath · 7/29
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Fath
وَلِلَّهِ جُنُودُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمًا ۝٧
Wa lillaahi junoodus samaawaati wal ard; wa kaanal laahu `azeezan hakeema
📖 Ni Yorùbá
Ti Allahu si ni awon omo ogun sanmo ati ile. Allahu si n je Alagbara, Ologbon
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 5-9 — Al-Fath

5لِّيُدْخِلَ الْمُؤْمِنِينَ وَالْمُؤْمِنَاتِ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا وَيُكَفِّرَ عَنْهُمْ سَيِّئَاتِهِمْ ۚ وَكَانَ ذَٰلِكَ عِندَ اللَّهِ فَوْزًا عَظِيمًا
(O se bee fun won) nitori ki O le mu awon onigbagbo ododo lokunrin ati onigbagbo ododo lobinrin wo inu awon Ogba Idera, eyi ti awon odo n san ni isale re, olusegbere ni won ninu re, ati nitori ki O le pa awon asise won re. Iyen si je erenje nla ni odo Allahu
6وَيُعَذِّبَ الْمُنَافِقِينَ وَالْمُنَافِقَاتِ وَالْمُشْرِكِينَ وَالْمُشْرِكَاتِ الظَّانِّينَ بِاللَّهِ ظَنَّ السَّوْءِ ۚ عَلَيْهِمْ دَائِرَةُ السَّوْءِ ۖ وَغَضِبَ اللَّهُ عَلَيْهِمْ وَلَعَنَهُمْ وَأَعَدَّ لَهُمْ جَهَنَّمَ ۖ وَسَاءَتْ مَصِيرًا
Ati nitori ki O le fiya je awon sobe-selu musulumi lokunrin ati awon sobe-selu musulumi lobinrin, pelu awon osebo lokunrin ati awon osebo lobinrin, awon elerokero nipa Allahu ni ti ero aburu. Apadasi aburu n be fun won. Allahu ti binu si won. O ti sebi le won. O si ti pese ina Jahnamo sile de won. O si buru ni ikangun
7وَلِلَّهِ جُنُودُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمًا
Ti Allahu si ni awon omo ogun sanmo ati ile. Allahu si n je Alagbara, Ologbon
8إِنَّا أَرْسَلْنَاكَ شَاهِدًا وَمُبَشِّرًا وَنَذِيرًا
Dajudaju Awa ran o nise (pe ki o je) olujerii, oniroo-idunnu ati olukilo
9لِّتُؤْمِنُوا بِاللَّهِ وَرَسُولِهِ وَتُعَزِّرُوهُ وَتُوَقِّرُوهُ وَتُسَبِّحُوهُ بُكْرَةً وَأَصِيلًا
nitori ki e le ni igbagbo ododo ninu Allahu ati Ojise Re, ati (nitori ki) e le se iranlowo fun (Ojise naa) ati nitori ki e le pataki re, ati nitori ki e le safomo fun (Allahu) ni owuro ati ni asale
Al-FathAtokọ Kurani
29Ẹsẹ
MedinanRevelation
7Ẹsẹ

Itumọ — Al-Fath 7

Surah Al-Fath Ẹsẹ 7 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti Allahu si ni awon omo ogun sanmo ati ile.…

Surah Ẹsẹ 7/29 — Al-Fath الفتح (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Fath Gbọ, Al-Fath Itumọ, Al-Fath mp3, Al-Fath pdf. Ẹsẹ 5–9. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers