Qaf · 22/45
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Qaf
لَّقَدْ كُنتَ فِي غَفْلَةٍ مِّنْ هَٰذَا فَكَشَفْنَا عَنكَ غِطَاءَكَ فَبَصَرُكَ الْيَوْمَ حَدِيدٌ ۝٢٢
Laqad kunta fee ghaf latim min haazaa fakashafnaa `anka ghitaaa`aka fabasarukal yawma hadeed
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju iwo ti wa ninu igbagbera nibi eyi. A si ti si ebibo (oju) re kuro fun o bayii. Nitori naa, iriran re yoo riran kedere ni oni

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 20-24 — Surah Qaf

20وَنُفِخَ فِي الصُّورِ ۚ ذَٰلِكَ يَوْمُ الْوَعِيدِ
Won a fon fere oniwo fun ajinde. Iyen ni ojo ileri naa
21وَجَاءَتْ كُلُّ نَفْسٍ مَّعَهَا سَائِقٌ وَشَهِيدٌ
Emi kookan yoo wa pelu oludari kan ati elerii kan (ninu awon molaika)
22لَّقَدْ كُنتَ فِي غَفْلَةٍ مِّنْ هَٰذَا فَكَشَفْنَا عَنكَ غِطَاءَكَ فَبَصَرُكَ الْيَوْمَ حَدِيدٌ
Dajudaju iwo ti wa ninu igbagbera nibi eyi. A si ti si ebibo (oju) re kuro fun o bayii. Nitori naa, iriran re yoo riran kedere ni oni
23وَقَالَ قَرِينُهُ هَٰذَا مَا لَدَيَّ عَتِيدٌ
(Molaika) alabaarin re yoo so pe: "Eyi ni ohun ti n be ni odo mi (gege bi akosile ise re)
24أَلْقِيَا فِي جَهَنَّمَ كُلَّ كَفَّارٍ عَنِيدٍ
E ju u sinu ina Jahanamo, gbogbo alaigbagbo olorikunkun
QafAtokọ Kurani
45Ẹsẹ
MeccanRevelation
22Ẹsẹ

Itumọ — Qaf 22

Surah Qaf Ẹsẹ 22 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju iwo ti wa ninu igbagbera nibi eyi. A si…

Surah Ẹsẹ 22/45 — Surah Qaf ق (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Qaf Gbọ, Surah Qaf Itumọ, Surah Qaf mp3, Surah Qaf pdf. Ẹsẹ 20–24. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers