Ar-Rahman · 19/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Ar-Rahman
مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ يَلْتَقِيَانِ ۝١٩
Marajal bahrayni yalta qiyaani
📖 Ni Yorùbá
(Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 17-21 — Ar-Rahman

17رَبُّ الْمَشْرِقَيْنِ وَرَبُّ الْمَغْرِبَيْنِ
Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji
18فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
19مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ يَلْتَقِيَانِ
(Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
20بَيْنَهُمَا بَرْزَخٌ لَّا يَبْغِيَانِ
Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko si le tayo enu-ala (re laaarin ara won)
21فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
19Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 19

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 19 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san…

Surah Ẹsẹ 19/78 — Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Ar-Rahman Gbọ, Ar-Rahman Itumọ, Ar-Rahman mp3, Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 17–21. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers