Al-Jumu'ah · 3/11
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Jumu'ah
وَآخَرِينَ مِنْهُمْ لَمَّا يَلْحَقُوا بِهِمْ ۚ وَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ ۝٣
Wa aakhareena minhum lammaa yalhaqoo bihim wa huwal `azeezul hakeem
📖 Ni Yorùbá
(Ise jije re tun wa fun) awon miiran ti won maa wa ninu awon (omoleyin re), amo ti won ko ti i rin kan won. (Allahu) Oun ni Alagbara, Ologbon
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 1-5 — Al-Jumu'ah

1يُسَبِّحُ لِلَّهِ مَا فِي السَّمَاوَاتِ وَمَا فِي الْأَرْضِ الْمَلِكِ الْقُدُّوسِ الْعَزِيزِ الْحَكِيمِ
Ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun to wa ninu ile n se afomo fun Allahu, Oba eda, Eni-Mimo julo, Alagbara, Ologbon
2هُوَ الَّذِي بَعَثَ فِي الْأُمِّيِّينَ رَسُولًا مِّنْهُمْ يَتْلُو عَلَيْهِمْ آيَاتِهِ وَيُزَكِّيهِمْ وَيُعَلِّمُهُمُ الْكِتَابَ وَالْحِكْمَةَ وَإِن كَانُوا مِن قَبْلُ لَفِي ضَلَالٍ مُّبِينٍ
Oun ni Eni ti O gbe dide laaarin awon alaimoonkomoonka (alainitira) Ojise kan lara won. O n ke awon ayah Re fun won. O n fo won mo (ninu ese). O si n ko won ni Tira ati ogbon ijinle (iyen, sunnah), bi o tile je pe teletele won ti wa ninu isina ponnbele
3وَآخَرِينَ مِنْهُمْ لَمَّا يَلْحَقُوا بِهِمْ ۚ وَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
(Ise jije re tun wa fun) awon miiran ti won maa wa ninu awon (omoleyin re), amo ti won ko ti i rin kan won. (Allahu) Oun ni Alagbara, Ologbon
4ذَٰلِكَ فَضْلُ اللَّهِ يُؤْتِيهِ مَن يَشَاءُ ۚ وَاللَّهُ ذُو الْفَضْلِ الْعَظِيمِ
Iyen ni oore ajulo Allahu. O n fun eni ti O ba fe. Allahu si ni Oloore-ajulo nla
5مَثَلُ الَّذِينَ حُمِّلُوا التَّوْرَاةَ ثُمَّ لَمْ يَحْمِلُوهَا كَمَثَلِ الْحِمَارِ يَحْمِلُ أَسْفَارًا ۚ بِئْسَ مَثَلُ الْقَوْمِ الَّذِينَ كَذَّبُوا بِآيَاتِ اللَّهِ ۚ وَاللَّهُ لَا يَهْدِي الْقَوْمَ الظَّالِمِينَ
Apejuwe ijo ti A fun ni Taorah, leyin naa ti won ko tele e, o da bi apejuwe ketekete ti o ru eru awon tira. Aburu ni apejuwe awon t’o pe awon ayah Allahu niro. Allahu ko si nii fi ona mo ijo alabosi
Al-Jumu'ahAtokọ Kurani
11Ẹsẹ
MedinanRevelation
3Ẹsẹ

Itumọ — Al-Jumu'ah 3

Surah Al-Jumu'ah Ẹsẹ 3 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Ise jije re tun wa fun) awon miiran ti won…

Surah Ẹsẹ 3/11 — Al-Jumu'ah الجمعة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Jumu'ah Gbọ, Al-Jumu'ah Itumọ, Al-Jumu'ah mp3, Al-Jumu'ah pdf. Ẹsẹ 1–5. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers