Hud · 78/123
Itumọ Aṣẹ ohun — Hud
وَجَاءَهُ قَوْمُهُ يُهْرَعُونَ إِلَيْهِ وَمِن قَبْلُ كَانُوا يَعْمَلُونَ السَّيِّئَاتِ ۚ قَالَ يَا قَوْمِ هَٰؤُلَاءِ بَنَاتِي هُنَّ أَطْهَرُ لَكُمْ ۖ فَاتَّقُوا اللَّهَ وَلَا تُخْزُونِ فِي ضَيْفِي ۖ أَلَيْسَ مِنكُمْ رَجُلٌ رَّشِيدٌ ۝٧٨
Wa jaaa`ahoo qawmuhoo yuhra`oona ilaihi wa min qablu kaanoo ya`maloonas saiyiaat; qaala yaa qawmi haaa`ulaaa`i banaatee hunna atharu lakum fattaqul laaha wa laa tukhzooni fee daifee alaisa minkum rajulur rasheed
📖 Ni Yorùbá
Awon eniyan re wa ba a, ti won n sare gbon wa si odo re. Teletele won si ti n se ise aburu (bii ibalopo laaarin okunrin ati okunrin). O so pe: "Eyin eniyan mi, awon wonyen ni omobinrin mi, won mo julo fun yin (lati fi saya). Nitori naa, e beru Allahu. Ki e si ma se doju ti mi lodo alejo mi. Se ko si okunrin olumona kan ninu yin ni
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 76-80 — Hud

76يَا إِبْرَاهِيمُ أَعْرِضْ عَنْ هَٰذَا ۖ إِنَّهُ قَدْ جَاءَ أَمْرُ رَبِّكَ ۖ وَإِنَّهُمْ آتِيهِمْ عَذَابٌ غَيْرُ مَرْدُودٍ
(Anabi) ’Ibrohim, seri kuro nibi eyi. Dajudaju ase Oluwa re ti de. Ati pe dajudaju awon ni iya ti ko se e da pada yoo de ba
77وَلَمَّا جَاءَتْ رُسُلُنَا لُوطًا سِيءَ بِهِمْ وَضَاقَ بِهِمْ ذَرْعًا وَقَالَ هَٰذَا يَوْمٌ عَصِيبٌ
Nigba ti awon Ojise Wa de ba (Anabi) Lut, o banuje nitori won. Agbara re ko si ka oro won mo. O si so pe: “Eyi ni ojo t’o le pupo.”
78وَجَاءَهُ قَوْمُهُ يُهْرَعُونَ إِلَيْهِ وَمِن قَبْلُ كَانُوا يَعْمَلُونَ السَّيِّئَاتِ ۚ قَالَ يَا قَوْمِ هَٰؤُلَاءِ بَنَاتِي هُنَّ أَطْهَرُ لَكُمْ ۖ فَاتَّقُوا اللَّهَ وَلَا تُخْزُونِ فِي ضَيْفِي ۖ أَلَيْسَ مِنكُمْ رَجُلٌ رَّشِيدٌ
Awon eniyan re wa ba a, ti won n sare gbon wa si odo re. Teletele won si ti n se ise aburu (bii ibalopo laaarin okunrin ati okunrin). O so pe: "Eyin eniyan mi, awon wonyen ni omobinrin mi, won mo julo fun yin (lati fi saya). Nitori naa, e beru Allahu. Ki e si ma se doju ti mi lodo alejo mi. Se ko si okunrin olumona kan ninu yin ni
79قَالُوا لَقَدْ عَلِمْتَ مَا لَنَا فِي بَنَاتِكَ مِنْ حَقٍّ وَإِنَّكَ لَتَعْلَمُ مَا نُرِيدُ
Won wi pe: “Iwo kuku ti mo pe awa ko letoo kan si awon omobinrin re. O si ti mo nnkan ti a n fe.”
80قَالَ لَوْ أَنَّ لِي بِكُمْ قُوَّةً أَوْ آوِي إِلَىٰ رُكْنٍ شَدِيدٍ
O so pe: "Ti o ba je pe dajudaju agbara kan wa fun mi lori yin ni, tabi (pe) mo le darapo mo ebi kan t’o lagbara ni, (emi iba di yin lowo nibi aburu yin)
HudAtokọ Kurani
123Ẹsẹ
MeccanRevelation
78Ẹsẹ

Itumọ — Hud 78

Surah Hud Ẹsẹ 78 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon eniyan re wa ba a, ti won n sare…

Surah Ẹsẹ 78/123 — Hud هود (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Hud Gbọ, Hud Itumọ, Hud mp3, Hud pdf. Ẹsẹ 76–80. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers