Al-Baqarah · 270/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
وَمَا أَنفَقْتُم مِّن نَّفَقَةٍ أَوْ نَذَرْتُم مِّن نَّذْرٍ فَإِنَّ اللَّهَ يَعْلَمُهُ ۗ وَمَا لِلظَّالِمِينَ مِنْ أَنصَارٍ ۝٢٧٠
Wa maaa anfaqtum min nafaqatin aw nazartum min nazrin fa innal laaha ya`lamuh; wa maa lizzaalimeena min ansaar
📖 Ni Yorùbá
Ohunkohun ti e ba na ni inawo tabi (ohunkohun) ti e ba je ni eje, dajudaju Allahu mo on. Ko si nii si oluranlowo kan fun awon alabosi

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 268-272 — Al-Baqarah

268الشَّيْطَانُ يَعِدُكُمُ الْفَقْرَ وَيَأْمُرُكُم بِالْفَحْشَاءِ ۖ وَاللَّهُ يَعِدُكُم مَّغْفِرَةً مِّنْهُ وَفَضْلًا ۗ وَاللَّهُ وَاسِعٌ عَلِيمٌ
Esu n fi osi deru ba yin, o si n pa yin ni ase ibaje sise. Allahu si n se adehun aforijin ati oore ajulo lati odo Re fun yin. Allahu ni Olugbaaye, Onimo
269يُؤْتِي الْحِكْمَةَ مَن يَشَاءُ ۚ وَمَن يُؤْتَ الْحِكْمَةَ فَقَدْ أُوتِيَ خَيْرًا كَثِيرًا ۗ وَمَا يَذَّكَّرُ إِلَّا أُولُو الْأَلْبَابِ
O n fun eni ti O ba fe ni oye ijinle. Eni ti A ba si fun ni oye ijinle, A kuku ti fun un ni oore pupo. Eni kan ko nii lo iranti afi awon onilaakaye
270وَمَا أَنفَقْتُم مِّن نَّفَقَةٍ أَوْ نَذَرْتُم مِّن نَّذْرٍ فَإِنَّ اللَّهَ يَعْلَمُهُ ۗ وَمَا لِلظَّالِمِينَ مِنْ أَنصَارٍ
Ohunkohun ti e ba na ni inawo tabi (ohunkohun) ti e ba je ni eje, dajudaju Allahu mo on. Ko si nii si oluranlowo kan fun awon alabosi
271إِن تُبْدُوا الصَّدَقَاتِ فَنِعِمَّا هِيَ ۖ وَإِن تُخْفُوهَا وَتُؤْتُوهَا الْفُقَرَاءَ فَهُوَ خَيْرٌ لَّكُمْ ۚ وَيُكَفِّرُ عَنكُم مِّن سَيِّئَاتِكُمْ ۗ وَاللَّهُ بِمَا تَعْمَلُونَ خَبِيرٌ
Ti e ba safi han awon saraa, o kuku dara. Ti e ba si fi pamo, ti e lo fun awon alaini, o si dara julo fun yin. Allahu si maa pa awon iwa aidaa yin re fun yin. Allahu si ni Alamotan nipa ohun ti e n se nise
272۞ لَّيْسَ عَلَيْكَ هُدَاهُمْ وَلَٰكِنَّ اللَّهَ يَهْدِي مَن يَشَاءُ ۗ وَمَا تُنفِقُوا مِنْ خَيْرٍ فَلِأَنفُسِكُمْ ۚ وَمَا تُنفِقُونَ إِلَّا ابْتِغَاءَ وَجْهِ اللَّهِ ۚ وَمَا تُنفِقُوا مِنْ خَيْرٍ يُوَفَّ إِلَيْكُمْ وَأَنتُمْ لَا تُظْلَمُونَ
Imona won ko si lorun re, sugbon Allahu l’O n fi eni ti O ba fe mona. Ohunkohun ti e ba n na ni ohun rere, fun emi ara yin ni. E o si nii nawo afi lati fi wa oju rere Allahu. Ohunkohun ti e ba si na ni ohun rere, A o san yin ni esan (re) ni ekun-rere. Won ko si nii sabosi si yin
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
270Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 270

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 270 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ohunkohun ti e ba na ni inawo tabi (ohunkohun) ti…

Surah Ẹsẹ 270/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 268–272. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers