Al-Anbiya · 96/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Anbiya
حَتَّىٰ إِذَا فُتِحَتْ يَأْجُوجُ وَمَأْجُوجُ وَهُم مِّن كُلِّ حَدَبٍ يَنسِلُونَ ۝٩٦
Hattaaa izaa futihat Yaajooju wa Maajooju wa hum min kulli hadabiny yansiloon
📖 Ni Yorùbá
(Won yoo wa ninu barsaku) titi A oo fi si awon Ya’juj ati Ma’juj sile. Awon (wonyi) yo si maa sare jade lati inu gbogbo aye giga

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 94-98 — Surah Al-Anbiya

94فَمَن يَعْمَلْ مِنَ الصَّالِحَاتِ وَهُوَ مُؤْمِنٌ فَلَا كُفْرَانَ لِسَعْيِهِ وَإِنَّا لَهُ كَاتِبُونَ
Nitori naa, enikeni ti o ba se ninu awon ise rere, ti o si je onigbagbo ododo, ko si kiko fun ise re. Ati pe dajudaju Awa maa se akosile re fun un
95وَحَرَامٌ عَلَىٰ قَرْيَةٍ أَهْلَكْنَاهَا أَنَّهُمْ لَا يَرْجِعُونَ
Eewo ni fun ara ilu kan ti A ti pare (pe ki o tun pada si aye); dajudaju won ko nii pada mo (si ile aye)
96حَتَّىٰ إِذَا فُتِحَتْ يَأْجُوجُ وَمَأْجُوجُ وَهُم مِّن كُلِّ حَدَبٍ يَنسِلُونَ
(Won yoo wa ninu barsaku) titi A oo fi si awon Ya’juj ati Ma’juj sile. Awon (wonyi) yo si maa sare jade lati inu gbogbo aye giga
97وَاقْتَرَبَ الْوَعْدُ الْحَقُّ فَإِذَا هِيَ شَاخِصَةٌ أَبْصَارُ الَّذِينَ كَفَرُوا يَا وَيْلَنَا قَدْ كُنَّا فِي غَفْلَةٍ مِّنْ هَٰذَا بَلْ كُنَّا ظَالِمِينَ
Adehun ododo naa sunmo pekipeki. Nigba naa, awon t’o sai gbagbo yoo maa ranju kale rangandan, (won yo si wi pe): “Egbe ni fun wa! Dajudaju awa ti wa ninu igbagbera nipa eyi. Rara, awa je alabosi ni.”
98إِنَّكُمْ وَمَا تَعْبُدُونَ مِن دُونِ اللَّهِ حَصَبُ جَهَنَّمَ أَنتُمْ لَهَا وَارِدُونَ
Dajudaju eyin ati nnkan ti e n josin fun leyin Allahu ni ikona Jahanamo; eyin yo si wo inu re
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
96Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 96

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 96 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Won yoo wa ninu barsaku) titi A oo fi si…

Surah Ẹsẹ 96/112 — Surah Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Anbiya Gbọ, Surah Al-Anbiya Itumọ, Surah Al-Anbiya mp3, Surah Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 94–98. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers