Al-Anbiya · 97/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Anbiya
وَاقْتَرَبَ الْوَعْدُ الْحَقُّ فَإِذَا هِيَ شَاخِصَةٌ أَبْصَارُ الَّذِينَ كَفَرُوا يَا وَيْلَنَا قَدْ كُنَّا فِي غَفْلَةٍ مِّنْ هَٰذَا بَلْ كُنَّا ظَالِمِينَ ۝٩٧
Waqtarabal wa`dul haqqu fa-izaa hiya shaakhisatun absaarul lazeena kafaroo yaawailanaa qad kunna fee ghaflatim min haaza bal kunnaa zaalimeen
📖 Ni Yorùbá
Adehun ododo naa sunmo pekipeki. Nigba naa, awon t’o sai gbagbo yoo maa ranju kale rangandan, (won yo si wi pe): “Egbe ni fun wa! Dajudaju awa ti wa ninu igbagbera nipa eyi. Rara, awa je alabosi ni.”
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 95-99 — Al-Anbiya

95وَحَرَامٌ عَلَىٰ قَرْيَةٍ أَهْلَكْنَاهَا أَنَّهُمْ لَا يَرْجِعُونَ
Eewo ni fun ara ilu kan ti A ti pare (pe ki o tun pada si aye); dajudaju won ko nii pada mo (si ile aye)
96حَتَّىٰ إِذَا فُتِحَتْ يَأْجُوجُ وَمَأْجُوجُ وَهُم مِّن كُلِّ حَدَبٍ يَنسِلُونَ
(Won yoo wa ninu barsaku) titi A oo fi si awon Ya’juj ati Ma’juj sile. Awon (wonyi) yo si maa sare jade lati inu gbogbo aye giga
97وَاقْتَرَبَ الْوَعْدُ الْحَقُّ فَإِذَا هِيَ شَاخِصَةٌ أَبْصَارُ الَّذِينَ كَفَرُوا يَا وَيْلَنَا قَدْ كُنَّا فِي غَفْلَةٍ مِّنْ هَٰذَا بَلْ كُنَّا ظَالِمِينَ
Adehun ododo naa sunmo pekipeki. Nigba naa, awon t’o sai gbagbo yoo maa ranju kale rangandan, (won yo si wi pe): “Egbe ni fun wa! Dajudaju awa ti wa ninu igbagbera nipa eyi. Rara, awa je alabosi ni.”
98إِنَّكُمْ وَمَا تَعْبُدُونَ مِن دُونِ اللَّهِ حَصَبُ جَهَنَّمَ أَنتُمْ لَهَا وَارِدُونَ
Dajudaju eyin ati nnkan ti e n josin fun leyin Allahu ni ikona Jahanamo; eyin yo si wo inu re
99لَوْ كَانَ هَٰؤُلَاءِ آلِهَةً مَّا وَرَدُوهَا ۖ وَكُلٌّ فِيهَا خَالِدُونَ
Ti o ba je pe awon wonyi ni olohun ni, won iba ti wo inu Ina. Olusegbere si ni eni kookan won ninu re
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
97Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 97

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 97 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Adehun ododo naa sunmo pekipeki. Nigba naa, awon t’o sai…

Surah Ẹsẹ 97/112 — Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Anbiya Gbọ, Al-Anbiya Itumọ, Al-Anbiya mp3, Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 95–99. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers