An-Nur · 8/64
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nur
وَيَدْرَأُ عَنْهَا الْعَذَابَ أَن تَشْهَدَ أَرْبَعَ شَهَادَاتٍ بِاللَّهِ ۙ إِنَّهُ لَمِنَ الْكَاذِبِينَ ۝٨
Wa yadra`u anhal `azaaba an tashhada arba`a shahaa daatim billaahi innahoo laminal kaazibeen
📖 Ni Yorùbá
Ohun ti o maa ye iya fun iyawo ni pe ki o fi Allahu jerii ni ee merin pe dajudaju oko oun wa ninu awon opuro
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 6-10 — An-Nur

6وَالَّذِينَ يَرْمُونَ أَزْوَاجَهُمْ وَلَمْ يَكُن لَّهُمْ شُهَدَاءُ إِلَّا أَنفُسُهُمْ فَشَهَادَةُ أَحَدِهِمْ أَرْبَعُ شَهَادَاتٍ بِاللَّهِ ۙ إِنَّهُ لَمِنَ الصَّادِقِينَ
Awon t’o n fi esun sina kan awon iyawo won, ti ko si si elerii fun won afi awon funra won, eri eni kookan won ni ki o fi Allahu jerii ni ee merin pe dajudaju oun wa ninu awon olododo
7وَالْخَامِسَةُ أَنَّ لَعْنَتَ اللَّهِ عَلَيْهِ إِن كَانَ مِنَ الْكَاذِبِينَ
Ee karun-un si ni pe ki ibi dandan Allahu maa ba oun, ti oun ba wa ninu awon opuro
8وَيَدْرَأُ عَنْهَا الْعَذَابَ أَن تَشْهَدَ أَرْبَعَ شَهَادَاتٍ بِاللَّهِ ۙ إِنَّهُ لَمِنَ الْكَاذِبِينَ
Ohun ti o maa ye iya fun iyawo ni pe ki o fi Allahu jerii ni ee merin pe dajudaju oko oun wa ninu awon opuro
9وَالْخَامِسَةَ أَنَّ غَضَبَ اللَّهِ عَلَيْهَا إِن كَانَ مِنَ الصَّادِقِينَ
Ee karun-un si ni pe ki ibinu Allahu maa ba oun, ti oko oun ba wa ninu awon olododo
10وَلَوْلَا فَضْلُ اللَّهِ عَلَيْكُمْ وَرَحْمَتُهُ وَأَنَّ اللَّهَ تَوَّابٌ حَكِيمٌ
Ti ki i ba se oore ajulo Allahu ati ike Re lori yin ni (Allahu iba maa tu asiri yin ni). Dajudaju Allahu ni Olugba-ironupiwada, Ologbon
An-NurAtokọ Kurani
64Ẹsẹ
MedinanRevelation
8Ẹsẹ

Itumọ — An-Nur 8

Surah An-Nur Ẹsẹ 8 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ohun ti o maa ye iya fun iyawo ni pe…

Surah Ẹsẹ 8/64 — An-Nur النور (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nur Gbọ, An-Nur Itumọ, An-Nur mp3, An-Nur pdf. Ẹsẹ 6–10. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers