Ash-Shu'ara · 12/227
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ash-Shu'ara
قَالَ رَبِّ إِنِّي أَخَافُ أَن يُكَذِّبُونِ ۝١٢
Qaala Rabbi inneee akhaafu ai yukazziboon
📖 Ni Yorùbá
O so pe: "Oluwa mi, dajudaju emi n beru pe won maa pe mi ni opuro

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 10-14 — Surah Ash-Shu'ara

10وَإِذْ نَادَىٰ رَبُّكَ مُوسَىٰ أَنِ ائْتِ الْقَوْمَ الظَّالِمِينَ
(Ranti) nigba ti Oluwa re pe (Anabi) Musa pe: "Lo ba ijo alabosi
11قَوْمَ فِرْعَوْنَ ۚ أَلَا يَتَّقُونَ
ijo Fir‘aon (ki o si so fun won) pe Se won ko nii beru (Allahu) ni
12قَالَ رَبِّ إِنِّي أَخَافُ أَن يُكَذِّبُونِ
O so pe: "Oluwa mi, dajudaju emi n beru pe won maa pe mi ni opuro
13وَيَضِيقُ صَدْرِي وَلَا يَنطَلِقُ لِسَانِي فَأَرْسِلْ إِلَىٰ هَارُونَ
O si maa je inira fun mi (ti won ba pe mi ni opuro). Ahon mi ko si ja gaaraga. Nitori naa, ranse si Harun
14وَلَهُمْ عَلَيَّ ذَنبٌ فَأَخَافُ أَن يَقْتُلُونِ
Ati pe mo ni ese kan lorun lodo won. Nitori naa, mo n beru pe won maa pa mi
Ash-Shu'araAtokọ Kurani
227Ẹsẹ
MeccanRevelation
12Ẹsẹ

Itumọ — Ash-Shu'ara 12

Surah Ash-Shu'ara Ẹsẹ 12 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : O so pe: "Oluwa mi, dajudaju emi n beru pe…

Surah Ẹsẹ 12/227 — Surah Ash-Shu'ara الشعراء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ash-Shu'ara Gbọ, Surah Ash-Shu'ara Itumọ, Surah Ash-Shu'ara mp3, Surah Ash-Shu'ara pdf. Ẹsẹ 10–14. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers