Aal-Imran · 2/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
اللَّهُ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الْحَيُّ الْقَيُّومُ ۝٢
Allaahu laaa ilaaha illaa Huwal Haiyul Qaiyoom
📖 Ni Yorùbá
Allahu, ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun, Alaaye, Alamojuuto-eda
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 1-4 — Aal-Imran

1الم
’Alif lam mim
2اللَّهُ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الْحَيُّ الْقَيُّومُ
Allahu, ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun, Alaaye, Alamojuuto-eda
3نَزَّلَ عَلَيْكَ الْكِتَابَ بِالْحَقِّ مُصَدِّقًا لِّمَا بَيْنَ يَدَيْهِ وَأَنزَلَ التَّوْرَاةَ وَالْإِنجِيلَ
O so Tira (al-Ƙur’an) kale fun o pelu ododo, ti o n fi ohun t’o je ododo rinle nipa eyi t’o wa siwaju re. O si so Taorah ati ’Injil kale
4مِن قَبْلُ هُدًى لِّلنَّاسِ وَأَنزَلَ الْفُرْقَانَ ۗ إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا بِآيَاتِ اللَّهِ لَهُمْ عَذَابٌ شَدِيدٌ ۗ وَاللَّهُ عَزِيزٌ ذُو انتِقَامٍ
ni isaaju. Imona si ni fun awon eniyan.1 O tun so oro-ipinya (oro t’o n sepinya laaarin ododo ati iro) kale.2 Dajudaju awon t’o sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, iya t’o le n be fun won. Allahu si ni Alagbara, Olugbesan
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
2Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 2

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 2 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Allahu, ko si olohun kan ti ijosin to si afi…

Surah Ẹsẹ 2/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 1–4. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers