Al-Fath · 23/29
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Fath
سُنَّةَ اللَّهِ الَّتِي قَدْ خَلَتْ مِن قَبْلُ ۖ وَلَن تَجِدَ لِسُنَّةِ اللَّهِ تَبْدِيلًا ۝٢٣
Sunnatal laahil latee qad khalat min qablu wa lan tajida lisunnatil laahi tabdeelaa
📖 Ni Yorùbá
Ise Allahu, eyi t’o ti sele siwaju (ni eyi). O o si nii ri iyipada fun ise Allahu (lori awon ota Re)
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 21-25 — Al-Fath

21وَأُخْرَىٰ لَمْ تَقْدِرُوا عَلَيْهَا قَدْ أَحَاطَ اللَّهُ بِهَا ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرًا
Ati omiran ti e o lagbara lori re, (amo ti) Allahu ti rokirika re. Allahu si n je Alagbara lori gbogbo nnkan
22وَلَوْ قَاتَلَكُمُ الَّذِينَ كَفَرُوا لَوَلَّوُا الْأَدْبَارَ ثُمَّ لَا يَجِدُونَ وَلِيًّا وَلَا نَصِيرًا
Ti o ba je pe awon t’o sai gbagbo gbogun dide si yin ni, won iba peyin da (lati sagun fun yin). Leyin naa, won ko nii ri alaabo tabi alaranse kan
23سُنَّةَ اللَّهِ الَّتِي قَدْ خَلَتْ مِن قَبْلُ ۖ وَلَن تَجِدَ لِسُنَّةِ اللَّهِ تَبْدِيلًا
Ise Allahu, eyi t’o ti sele siwaju (ni eyi). O o si nii ri iyipada fun ise Allahu (lori awon ota Re)
24وَهُوَ الَّذِي كَفَّ أَيْدِيَهُمْ عَنكُمْ وَأَيْدِيَكُمْ عَنْهُم بِبَطْنِ مَكَّةَ مِن بَعْدِ أَنْ أَظْفَرَكُمْ عَلَيْهِمْ ۚ وَكَانَ اللَّهُ بِمَا تَعْمَلُونَ بَصِيرًا
Oun si ni Eni ti O ko won lowo ro fun yin. O si ko eyin naa lowo ro fun won ninu ilu Mokkah leyin igba ti O ti fi yin bori won. Allahu si n je Oluriran nipa ohun ti e n se nise
25هُمُ الَّذِينَ كَفَرُوا وَصَدُّوكُمْ عَنِ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ وَالْهَدْيَ مَعْكُوفًا أَن يَبْلُغَ مَحِلَّهُ ۚ وَلَوْلَا رِجَالٌ مُّؤْمِنُونَ وَنِسَاءٌ مُّؤْمِنَاتٌ لَّمْ تَعْلَمُوهُمْ أَن تَطَئُوهُمْ فَتُصِيبَكُم مِّنْهُم مَّعَرَّةٌ بِغَيْرِ عِلْمٍ ۖ لِّيُدْخِلَ اللَّهُ فِي رَحْمَتِهِ مَن يَشَاءُ ۚ لَوْ تَزَيَّلُوا لَعَذَّبْنَا الَّذِينَ كَفَرُوا مِنْهُمْ عَذَابًا أَلِيمًا
Awon (osebo) ni awon t’o sai gbagbo, ti won se yin lori kuro ni Mosalasi Haram, ti won tun de eran ore mole ki o ma le de aye re. Ti ki i ba se ti awon okunrin (ti won ti di) onigbagbo ododo ati awon obinrin (ti won ti di) onigbagbo ododo (ninu ilu Mokkah), ti eyin ko si mo won, ki eyin ma lo pa won, ki eyin ma lo fara ko ese lati ara won nipase aimo, (Allahu iba ti ko yin lowo ro fun won. Allahu ko yin lowo ro fun won se) nitori ki O le fi eni ti o ba fe sinu ike Re. Ti o ba je pe won wa ni otooto ni (onigbagbo ododo loto, alaigbagbo loto), Awa iba je awon t’o sai gbagbo ninu won ni iya eleta-elero
Al-FathAtokọ Kurani
29Ẹsẹ
MedinanRevelation
23Ẹsẹ

Itumọ — Al-Fath 23

Surah Al-Fath Ẹsẹ 23 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ise Allahu, eyi t’o ti sele siwaju (ni eyi). O…

Surah Ẹsẹ 23/29 — Al-Fath الفتح (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Fath Gbọ, Al-Fath Itumọ, Al-Fath mp3, Al-Fath pdf. Ẹsẹ 21–25. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers