Ar-Rahman · 20/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
بَيْنَهُمَا بَرْزَخٌ لَّا يَبْغِيَانِ ۝٢٠
Bainahumaa barzakhul laa yabghiyaan
📖 Ni Yorùbá
Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko si le tayo enu-ala (re laaarin ara won)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 18-22 — Surah Ar-Rahman

18فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
19مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ يَلْتَقِيَانِ
(Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
20بَيْنَهُمَا بَرْزَخٌ لَّا يَبْغِيَانِ
Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko si le tayo enu-ala (re laaarin ara won)
21فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
22يَخْرُجُ مِنْهُمَا اللُّؤْلُؤُ وَالْمَرْجَانُ
Okuta oniyebiye ati ileke iyun n jade ninu awon (odo) mejeeji naa
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
20Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 20

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 20 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko…

Surah Ẹsẹ 20/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 18–22. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers