Al-A'raf · 93/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-A'raf
فَتَوَلَّىٰ عَنْهُمْ وَقَالَ يَا قَوْمِ لَقَدْ أَبْلَغْتُكُمْ رِسَالَاتِ رَبِّي وَنَصَحْتُ لَكُمْ ۖ فَكَيْفَ آسَىٰ عَلَىٰ قَوْمٍ كَافِرِينَ ۝٩٣
Fatawalla `anhum wa qaala yaa qawmi laqad ablaghtukum Risaalaati Rabbee wa nasahtu lakum fakaifa aasaa`alaa qawmin kaafireen
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, (Su‘aeb) seri kuro lodo won, o si so pe: “Eyin ijo mi, mo kuku ti je awon ise Oluwa mi fun yin. Mo si ti fun yin ni imoran rere. Bawo ni emi yoo se tun maa banuje lori ijo alaigbagbo.”

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 91-95 — Surah Al-A'raf

91فَأَخَذَتْهُمُ الرَّجْفَةُ فَأَصْبَحُوا فِي دَارِهِمْ جَاثِمِينَ
Nitori naa, ohun igbe lile t’o mi ile titi gba won mu. Won si di eni t’o da lule, ti won ti doku sinu ilu won
92الَّذِينَ كَذَّبُوا شُعَيْبًا كَأَن لَّمْ يَغْنَوْا فِيهَا ۚ الَّذِينَ كَذَّبُوا شُعَيْبًا كَانُوا هُمُ الْخَاسِرِينَ
Awon t’o pe Su‘aeb lopuro si da bi eni ti ko gbe ninu ilu won ri; awon t’o pe Su‘aeb lopuro ni won je eni ofo
93فَتَوَلَّىٰ عَنْهُمْ وَقَالَ يَا قَوْمِ لَقَدْ أَبْلَغْتُكُمْ رِسَالَاتِ رَبِّي وَنَصَحْتُ لَكُمْ ۖ فَكَيْفَ آسَىٰ عَلَىٰ قَوْمٍ كَافِرِينَ
Nitori naa, (Su‘aeb) seri kuro lodo won, o si so pe: “Eyin ijo mi, mo kuku ti je awon ise Oluwa mi fun yin. Mo si ti fun yin ni imoran rere. Bawo ni emi yoo se tun maa banuje lori ijo alaigbagbo.”
94وَمَا أَرْسَلْنَا فِي قَرْيَةٍ مِّن نَّبِيٍّ إِلَّا أَخَذْنَا أَهْلَهَا بِالْبَأْسَاءِ وَالضَّرَّاءِ لَعَلَّهُمْ يَضَّرَّعُونَ
A o ran Anabi kan si ilu kan lai je pe A fi iponju ati inira kan awon ara ilu naa nitori ki won le rawo-rase (si Allahu)
95ثُمَّ بَدَّلْنَا مَكَانَ السَّيِّئَةِ الْحَسَنَةَ حَتَّىٰ عَفَوا وَّقَالُوا قَدْ مَسَّ آبَاءَنَا الضَّرَّاءُ وَالسَّرَّاءُ فَأَخَذْنَاهُم بَغْتَةً وَهُمْ لَا يَشْعُرُونَ
Leyin naa, A fi (ohun) rere ropo aburu (fun won) titi won fi po (lonka ati loro). Won si wi pe: “Owo inira ati idera kuku ti kan awon baba wa ri.” Nitori naa, A gba won mu lojiji, won ko si fura
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
93Ẹsẹ

Itumọ — Al-A'raf 93

Surah Al-A'raf Ẹsẹ 93 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, (Su‘aeb) seri kuro lodo won, o si so…

Surah Ẹsẹ 93/206 — Surah Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-A'raf Gbọ, Surah Al-A'raf Itumọ, Surah Al-A'raf mp3, Surah Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 91–95. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers