Nuh · 22/28
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Nuh
وَمَكَرُوا مَكْرًا كُبَّارًا ۝٢٢
Wa makaroo makran kubbaaraa
📖 Ni Yorùbá
Won si dete ni ete t’o tobi

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 20-24 — Surah Nuh

20لِّتَسْلُكُوا مِنْهَا سُبُلًا فِجَاجًا
nitori ki e le to awon oju ona fife gbegede lori re
21قَالَ نُوحٌ رَّبِّ إِنَّهُمْ عَصَوْنِي وَاتَّبَعُوا مَن لَّمْ يَزِدْهُ مَالُهُ وَوَلَدُهُ إِلَّا خَسَارًا
(Anabi) Nuh so pe: "Oluwa mi, dajudaju won yapa mi. Won si tele eni ti dukia re ati omo re ko se alekun kan fun bi ko se ofo
22وَمَكَرُوا مَكْرًا كُبَّارًا
Won si dete ni ete t’o tobi
23وَقَالُوا لَا تَذَرُنَّ آلِهَتَكُمْ وَلَا تَذَرُنَّ وَدًّا وَلَا سُوَاعًا وَلَا يَغُوثَ وَيَعُوقَ وَنَسْرًا
Won si wi pe: "E ma se fi awon orisa yin sile. E ma se fi orisa Wadd, Suwa‘u, Yeguth, Ye‘uƙ ati Nasr sile
24وَقَدْ أَضَلُّوا كَثِيرًا ۖ وَلَا تَزِدِ الظَّالِمِينَ إِلَّا ضَلَالًا
Dajudaju won ti ko opolopo sina. (Oluwa mi) ma se je ki awon alabosi lekun ni kini kan bi ko se isina
NuhAtokọ Kurani
28Ẹsẹ
MeccanRevelation
22Ẹsẹ

Itumọ — Nuh 22

Surah Nuh Ẹsẹ 22 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won si dete ni ete t’o tobi

Surah Ẹsẹ 22/28 — Surah Nuh نوح (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Nuh Gbọ, Surah Nuh Itumọ, Surah Nuh mp3, Surah Nuh pdf. Ẹsẹ 20–24. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers