Maryam · 28/98
Itumọ Aṣẹ ohun — Maryam
يَا أُخْتَ هَارُونَ مَا كَانَ أَبُوكِ امْرَأَ سَوْءٍ وَمَا كَانَتْ أُمُّكِ بَغِيًّا ۝٢٨
Yaaa ukkhta Haaroona maa kaana abokim ra-a saw`inw wa maa kaanat ummuki baghiyyaa
📖 Ni Yorùbá
Arabinrin Harun, baba re ki i se eniyan buruku. Ati pe iya re ki i se alagbere
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 26-30 — Maryam

26فَكُلِي وَاشْرَبِي وَقَرِّي عَيْنًا ۖ فَإِمَّا تَرَيِنَّ مِنَ الْبَشَرِ أَحَدًا فَقُولِي إِنِّي نَذَرْتُ لِلرَّحْمَٰنِ صَوْمًا فَلَنْ أُكَلِّمَ الْيَوْمَ إِنسِيًّا
Nitori naa, je, mu ki oju re si tutu. Ti o ba si ri eni kan ninu abara, so fun un pe: "Dajudaju mo jejee ikenuro fun Ajoke-aye. Nitori naa, mi o nii ba eniyan kan soro ni oni
27فَأَتَتْ بِهِ قَوْمَهَا تَحْمِلُهُ ۖ قَالُوا يَا مَرْيَمُ لَقَدْ جِئْتِ شَيْئًا فَرِيًّا
O si mu omo naa wa ba awon eniyan re (ni eni ti) o gbe e dani. Won so pe: "Moryam, dajudaju o ti gbe nnkan aburu nla wa
28يَا أُخْتَ هَارُونَ مَا كَانَ أَبُوكِ امْرَأَ سَوْءٍ وَمَا كَانَتْ أُمُّكِ بَغِيًّا
Arabinrin Harun, baba re ki i se eniyan buruku. Ati pe iya re ki i se alagbere
29فَأَشَارَتْ إِلَيْهِ ۖ قَالُوا كَيْفَ نُكَلِّمُ مَن كَانَ فِي الْمَهْدِ صَبِيًّا
O si toka si omo naa. Won so pe: “Bawo ni a o se ba eni t’o wa lori ite, t’o je omo oponlo soro?”
30قَالَ إِنِّي عَبْدُ اللَّهِ آتَانِيَ الْكِتَابَ وَجَعَلَنِي نَبِيًّا
(Omo naa) soro pe: "Dajudaju eru Allahu ni emi. (Allahu) fun mi ni Tira. O si se mi ni Anabi. eda ti o n bowo fun ilana ati ofin Olohun eda ti o juwo juse sile fun ilana ati ofin Olohun ati eda ti o n josin fun Olohun labe ilana ati ofin Olohun. Eda naa ko si nii yonu si ilana ati ofin miiran t’o yato si ti Olohun.” Eni ti o ba n se iwonyen fun ohun miiran tabi elomiiran but with my flesh I am a slave to the law of sin.” Itumo: “Nitori naa nigba naa pelu emi mi pelu okan ati ara wa ni a fi gba lati wa labe ofin Re. Iwonba asise ti a ba si fi ara se gege bi adamo eniyan ironupiwada ati itoro aforijin ni odo Allahu ni ona abayo lori re. Alaforijin
MaryamAtokọ Kurani
98Ẹsẹ
MeccanRevelation
28Ẹsẹ

Itumọ — Maryam 28

Surah Maryam Ẹsẹ 28 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Arabinrin Harun, baba re ki i se eniyan buruku. Ati…

Surah Ẹsẹ 28/98 — Maryam مريم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Maryam Gbọ, Maryam Itumọ, Maryam mp3, Maryam pdf. Ẹsẹ 26–30. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers