Al-Baqarah · 146/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
الَّذِينَ آتَيْنَاهُمُ الْكِتَابَ يَعْرِفُونَهُ كَمَا يَعْرِفُونَ أَبْنَاءَهُمْ ۖ وَإِنَّ فَرِيقًا مِّنْهُمْ لَيَكْتُمُونَ الْحَقَّ وَهُمْ يَعْلَمُونَ ۝١٤٦
Allazeena aatainaahumul kitaaba ya`rifoonahoo kamaa ya`rifoona abnaaa`ahum wa inna fareeqam minhum layaktumoonal haqqa wa hum ya`lamoon
📖 Ni Yorùbá
Awon ti A fun ni Tira, won mo Anabi (sollalahu alayhi wa sallam) gege bi won se mo awon omo won. Dajudaju awon ijo kan wa ninu won ti won kuku n fi ododo pamo; won si mo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 144-148 — Surah Al-Baqarah

144قَدْ نَرَىٰ تَقَلُّبَ وَجْهِكَ فِي السَّمَاءِ ۖ فَلَنُوَلِّيَنَّكَ قِبْلَةً تَرْضَاهَا ۚ فَوَلِّ وَجْهَكَ شَطْرَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ ۚ وَحَيْثُ مَا كُنتُمْ فَوَلُّوا وُجُوهَكُمْ شَطْرَهُ ۗ وَإِنَّ الَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ لَيَعْلَمُونَ أَنَّهُ الْحَقُّ مِن رَّبِّهِمْ ۗ وَمَا اللَّهُ بِغَافِلٍ عَمَّا يَعْمَلُونَ
A kuku ri yiyi ti o n yi oju re si sanmo. Nitori naa, A o doju re ko Ƙiblah kan ti o yonu si; nitori naa, koju re si agbegbe Mosalasi Haram (ni Mokkah). Ibikibi ti e ba tun wa, e koju yin si agbegbe re. Dajudaju awon ti A fun ni Tira kuku mo pe dajudaju ododo ni (ase Ƙiblah) lati odo Oluwa won. Allahu ko si nii gbagbe ohun ti won n se nise
145وَلَئِنْ أَتَيْتَ الَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ بِكُلِّ آيَةٍ مَّا تَبِعُوا قِبْلَتَكَ ۚ وَمَا أَنتَ بِتَابِعٍ قِبْلَتَهُمْ ۚ وَمَا بَعْضُهُم بِتَابِعٍ قِبْلَةَ بَعْضٍ ۚ وَلَئِنِ اتَّبَعْتَ أَهْوَاءَهُم مِّن بَعْدِ مَا جَاءَكَ مِنَ الْعِلْمِ ۙ إِنَّكَ إِذًا لَّمِنَ الظَّالِمِينَ
Dajudaju ti o ba fun awon ti A fun ni Tira ni gbogbo ayah, won ko nii tele Ƙiblah re. Iwo naa ko gbodo tele Ƙiblah won. Apa kan won ko si nii tele Ƙiblah apa kan. Dajudaju ti o ba tele ife-inu won leyin ohun ti o de ba o ninu imo, dajudaju nigba naa iwo wa ninu awon alabosi
146الَّذِينَ آتَيْنَاهُمُ الْكِتَابَ يَعْرِفُونَهُ كَمَا يَعْرِفُونَ أَبْنَاءَهُمْ ۖ وَإِنَّ فَرِيقًا مِّنْهُمْ لَيَكْتُمُونَ الْحَقَّ وَهُمْ يَعْلَمُونَ
Awon ti A fun ni Tira, won mo Anabi (sollalahu alayhi wa sallam) gege bi won se mo awon omo won. Dajudaju awon ijo kan wa ninu won ti won kuku n fi ododo pamo; won si mo
147الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ ۖ فَلَا تَكُونَنَّ مِنَ الْمُمْتَرِينَ
Ododo naa wa lati odo Oluwa re. Nitori naa, o o gbodo wa lara awon oniyemeji
148وَلِكُلٍّ وِجْهَةٌ هُوَ مُوَلِّيهَا ۖ فَاسْتَبِقُوا الْخَيْرَاتِ ۚ أَيْنَ مَا تَكُونُوا يَأْتِ بِكُمُ اللَّهُ جَمِيعًا ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Ikookan (ijo elesin) l’o ni ibukojusi t’o n koju si. Nitori naa, e yara gbawaju nibi awon ise rere. Ibikibi ti e ba wa, Allahu yo mu gbogbo yin wa (ni Ojo Ajinde). Dajudaju Alagbara ni Allahu lori gbogbo nnkan
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
146Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 146

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 146 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon ti A fun ni Tira, won mo Anabi (sollalahu…

Surah Ẹsẹ 146/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 144–148. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers