Al-Baqarah · 268/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
الشَّيْطَانُ يَعِدُكُمُ الْفَقْرَ وَيَأْمُرُكُم بِالْفَحْشَاءِ ۖ وَاللَّهُ يَعِدُكُم مَّغْفِرَةً مِّنْهُ وَفَضْلًا ۗ وَاللَّهُ وَاسِعٌ عَلِيمٌ ۝٢٦٨
Ash Shaitaanu ya`idukumul faqra wa yaamurukum bilfahshaaa`i wallaahu ya`idukum maghfiratam minhu wa fadlaa; wallaahu Waasi`un `Aleem
📖 Ni Yorùbá
Esu n fi osi deru ba yin, o si n pa yin ni ase ibaje sise. Allahu si n se adehun aforijin ati oore ajulo lati odo Re fun yin. Allahu ni Olugbaaye, Onimo
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 266-270 — Al-Baqarah

266أَيَوَدُّ أَحَدُكُمْ أَن تَكُونَ لَهُ جَنَّةٌ مِّن نَّخِيلٍ وَأَعْنَابٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ لَهُ فِيهَا مِن كُلِّ الثَّمَرَاتِ وَأَصَابَهُ الْكِبَرُ وَلَهُ ذُرِّيَّةٌ ضُعَفَاءُ فَأَصَابَهَا إِعْصَارٌ فِيهِ نَارٌ فَاحْتَرَقَتْ ۗ كَذَٰلِكَ يُبَيِّنُ اللَّهُ لَكُمُ الْآيَاتِ لَعَلَّكُمْ تَتَفَكَّرُونَ
Nje eni kan ninu yin nifee si ki oun ni ogba oko dabinu ati ajara, ti awon odo n san ni abe re, ti orisirisi eso tun wa fun un ninu re, ki ogbo de ba a, o si ni awon omo weere ti ko lagbara (ise oko sise), ki ategun lile ti ina n be ninu re kolu oko naa, ki o si jona? Bayen ni Allahu se n s’alaye awon ayah naa fun yin nitori ki e le ronu jinle
267يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا أَنفِقُوا مِن طَيِّبَاتِ مَا كَسَبْتُمْ وَمِمَّا أَخْرَجْنَا لَكُم مِّنَ الْأَرْضِ ۖ وَلَا تَيَمَّمُوا الْخَبِيثَ مِنْهُ تُنفِقُونَ وَلَسْتُم بِآخِذِيهِ إِلَّا أَن تُغْمِضُوا فِيهِ ۚ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ غَنِيٌّ حَمِيدٌ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e na ninu awon nnkan daadaa ti e se nise ati ninu awon nnkan ti A mu jade fun yin lati inu ile. E ma se gbero lati na ninu eyi ti ko dara. Eyin naa ko nii gba a afi ki e diju gba a. Ki e si mo pe dajudaju Allahu ni Oloro, Eleyin
268الشَّيْطَانُ يَعِدُكُمُ الْفَقْرَ وَيَأْمُرُكُم بِالْفَحْشَاءِ ۖ وَاللَّهُ يَعِدُكُم مَّغْفِرَةً مِّنْهُ وَفَضْلًا ۗ وَاللَّهُ وَاسِعٌ عَلِيمٌ
Esu n fi osi deru ba yin, o si n pa yin ni ase ibaje sise. Allahu si n se adehun aforijin ati oore ajulo lati odo Re fun yin. Allahu ni Olugbaaye, Onimo
269يُؤْتِي الْحِكْمَةَ مَن يَشَاءُ ۚ وَمَن يُؤْتَ الْحِكْمَةَ فَقَدْ أُوتِيَ خَيْرًا كَثِيرًا ۗ وَمَا يَذَّكَّرُ إِلَّا أُولُو الْأَلْبَابِ
O n fun eni ti O ba fe ni oye ijinle. Eni ti A ba si fun ni oye ijinle, A kuku ti fun un ni oore pupo. Eni kan ko nii lo iranti afi awon onilaakaye
270وَمَا أَنفَقْتُم مِّن نَّفَقَةٍ أَوْ نَذَرْتُم مِّن نَّذْرٍ فَإِنَّ اللَّهَ يَعْلَمُهُ ۗ وَمَا لِلظَّالِمِينَ مِنْ أَنصَارٍ
Ohunkohun ti e ba na ni inawo tabi (ohunkohun) ti e ba je ni eje, dajudaju Allahu mo on. Ko si nii si oluranlowo kan fun awon alabosi
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
268Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 268

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 268 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Esu n fi osi deru ba yin, o si n…

Surah Ẹsẹ 268/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 266–270. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers