Al-Baqarah · 278/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اتَّقُوا اللَّهَ وَذَرُوا مَا بَقِيَ مِنَ الرِّبَا إِن كُنتُم مُّؤْمِنِينَ ٢٧٨
Transliteration
Yaaa ayyuhal lazeena aamanut taqul laaha wa zaroo maa baqiya minar ribaaa in kuntum mu`mineen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e beru Allahu, ki e si fi ohun t’o seku ninu ele sile, ti e ba je onigbagbo ododo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 276-280 — Surah Al-Baqarah
276يَمْحَقُ اللَّهُ الرِّبَا وَيُرْبِي الصَّدَقَاتِ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ كُلَّ كَفَّارٍ أَثِيمٍ
Allahu maa run owo ele. O si maa bu si awon ore. Allahu ko nifee gbogbo alaigbagbo, elese
277إِنَّ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ وَأَقَامُوا الصَّلَاةَ وَآتَوُا الزَّكَاةَ لَهُمْ أَجْرُهُمْ عِندَ رَبِّهِمْ وَلَا خَوْفٌ عَلَيْهِمْ وَلَا هُمْ يَحْزَنُونَ
Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won kirun, ti won si yo Zakah, esan won n be fun won ni odo Oluwa won. Ko si ipaya fun won. Won ko si nii banuje
278يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اتَّقُوا اللَّهَ وَذَرُوا مَا بَقِيَ مِنَ الرِّبَا إِن كُنتُم مُّؤْمِنِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e beru Allahu, ki e si fi ohun t’o seku ninu ele sile, ti e ba je onigbagbo ododo
279فَإِن لَّمْ تَفْعَلُوا فَأْذَنُوا بِحَرْبٍ مِّنَ اللَّهِ وَرَسُولِهِ ۖ وَإِن تُبْتُمْ فَلَكُمْ رُءُوسُ أَمْوَالِكُمْ لَا تَظْلِمُونَ وَلَا تُظْلَمُونَ
Ti e o ba se bee, e lo mo pe ogun kan lati odo Allahu ati Ojise Re (n bo wa ba yin). Ti e ba si ronu piwada, tiyin ni oju-owo yin. E o nii sabosi (si won). Won ko si nii sabosi si yin
280وَإِن كَانَ ذُو عُسْرَةٍ فَنَظِرَةٌ إِلَىٰ مَيْسَرَةٍ ۚ وَأَن تَصَدَّقُوا خَيْرٌ لَّكُمْ ۖ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ
Ti (onigbese) ba je eni ti ara n ni, e wo o niran di asiko idera. Ati pe ki e fi se saraa (fun un) loore julo fun yin, ti e ba mo
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
278Ẹsẹ
Itumọ — Al-Baqarah 278
Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 278 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ti e gbagbo ni ododo, e beru Allahu, ki…Surah Ẹsẹ 278/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 276–280. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








