Aal-Imran · 124/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
إِذْ تَقُولُ لِلْمُؤْمِنِينَ أَلَن يَكْفِيَكُمْ أَن يُمِدَّكُمْ رَبُّكُم بِثَلَاثَةِ آلَافٍ مِّنَ الْمَلَائِكَةِ مُنزَلِينَ ۝١٢٤
Iz taqoolu lilmu`mineena alai yakfiyakum ai-yumiddakum Rabbukum bisalaasati aalaafim minal malaaa`ikati munzaleen
📖 Ni Yorùbá
Ranti nigba ti o n so fun awon onigbagbo ododo pe: “Se ko nii to yin ti Oluwa yin ba se iranlowo fun yin pelu egberun meta ninu awon molaika, ti Won maa sokale?”

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 122-126 — Surah Aal-Imran

122إِذْ هَمَّت طَّائِفَتَانِ مِنكُمْ أَن تَفْشَلَا وَاللَّهُ وَلِيُّهُمَا ۗ وَعَلَى اللَّهِ فَلْيَتَوَكَّلِ الْمُؤْمِنُونَ
(Ranti) nigba ti ijo meji ninu yin fe sojo. Allahu si ni Alafeyinti awon mejeeji. Allahu si ni ki awon onigbagbo ododo gbarale
123وَلَقَدْ نَصَرَكُمُ اللَّهُ بِبَدْرٍ وَأَنتُمْ أَذِلَّةٌ ۖ فَاتَّقُوا اللَّهَ لَعَلَّكُمْ تَشْكُرُونَ
Allahu kuku fun yin ni isegun ni ogun Badr, nigba ti eyin je alailagbara. Nitori naa, e beru Allahu ki e le dupe (fun Un)
124إِذْ تَقُولُ لِلْمُؤْمِنِينَ أَلَن يَكْفِيَكُمْ أَن يُمِدَّكُمْ رَبُّكُم بِثَلَاثَةِ آلَافٍ مِّنَ الْمَلَائِكَةِ مُنزَلِينَ
Ranti nigba ti o n so fun awon onigbagbo ododo pe: “Se ko nii to yin ti Oluwa yin ba se iranlowo fun yin pelu egberun meta ninu awon molaika, ti Won maa sokale?”
125بَلَىٰ ۚ إِن تَصْبِرُوا وَتَتَّقُوا وَيَأْتُوكُم مِّن فَوْرِهِمْ هَٰذَا يُمْدِدْكُمْ رَبُّكُم بِخَمْسَةِ آلَافٍ مِّنَ الْمَلَائِكَةِ مُسَوِّمِينَ
Rara (o maa to wa.). Ti eyin ba se suuru, ti e si beru Allahu, ti awon (ota) ba de ba yin lojiji, Oluwa yin yoo ran yin lowo pelu egberun maarun ninu awon molaika pelu ami idanimo lara won
126وَمَا جَعَلَهُ اللَّهُ إِلَّا بُشْرَىٰ لَكُمْ وَلِتَطْمَئِنَّ قُلُوبُكُم بِهِ ۗ وَمَا النَّصْرُ إِلَّا مِنْ عِندِ اللَّهِ الْعَزِيزِ الْحَكِيمِ
Allahu ko se e lasan bi ko se ki o le je iro idunnu fun yin ati nitori ki okan yin le bale pelu re. Ko si aranse lori ota (lati ibi kan kan) bi ko se lati odo Allahu, Alagbara, Ologbon
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
124Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 124

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 124 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ranti nigba ti o n so fun awon onigbagbo ododo…

Surah Ẹsẹ 124/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 122–126. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers