Aal-Imran · 40/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
قَالَ رَبِّ أَنَّىٰ يَكُونُ لِي غُلَامٌ وَقَدْ بَلَغَنِيَ الْكِبَرُ وَامْرَأَتِي عَاقِرٌ ۖ قَالَ كَذَٰلِكَ اللَّهُ يَفْعَلُ مَا يَشَاءُ ٤٠
Transliteration
Qaala Rabbi annaa yakoonu lee ghulaamunw wa qad balaghaniyal kibaru wamraatee `aaqirun qaala kazaalikal laahu yaf`alu maa yashaaa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
(Zakariyya) so pe: “Oluwa mi, bawo ni emi yoo se ni omokunrin; mo ma ti dagbalagba, agan si ni obinrin mi?” (Molaika) so pe: “Bayen ni Allahu se n se ohun ti O ba fe.”
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 38-42 — Aal-Imran
38هُنَالِكَ دَعَا زَكَرِيَّا رَبَّهُ ۖ قَالَ رَبِّ هَبْ لِي مِن لَّدُنكَ ذُرِّيَّةً طَيِّبَةً ۖ إِنَّكَ سَمِيعُ الدُّعَاءِ
Ibeyen ni Zakariyya ti pe Oluwa re. O so pe: "Oluwa mi, ta mi ni ore aromodomo daadaa lati odo Re. Dajudaju Iwo ni Olugbo adua
39فَنَادَتْهُ الْمَلَائِكَةُ وَهُوَ قَائِمٌ يُصَلِّي فِي الْمِحْرَابِ أَنَّ اللَّهَ يُبَشِّرُكَ بِيَحْيَىٰ مُصَدِّقًا بِكَلِمَةٍ مِّنَ اللَّهِ وَسَيِّدًا وَحَصُورًا وَنَبِيًّا مِّنَ الصَّالِحِينَ
Nitori naa, awon molaika pe e nigba ti o n kirun lowo ninu ile ijosin, (won so pe): "Dajudaju Allahu n fun o ni iro idunnu nipa (bibi) Yahya. O maa fi ododo rinle nipa oro kan lati odo Allahu. (O maa je) asiwaju, ti ko si nii sunmo obinrin. (O maa je) Anabi. O si wa ninu awon eni rere
40قَالَ رَبِّ أَنَّىٰ يَكُونُ لِي غُلَامٌ وَقَدْ بَلَغَنِيَ الْكِبَرُ وَامْرَأَتِي عَاقِرٌ ۖ قَالَ كَذَٰلِكَ اللَّهُ يَفْعَلُ مَا يَشَاءُ
(Zakariyya) so pe: “Oluwa mi, bawo ni emi yoo se ni omokunrin; mo ma ti dagbalagba, agan si ni obinrin mi?” (Molaika) so pe: “Bayen ni Allahu se n se ohun ti O ba fe.”
41قَالَ رَبِّ اجْعَل لِّي آيَةً ۖ قَالَ آيَتُكَ أَلَّا تُكَلِّمَ النَّاسَ ثَلَاثَةَ أَيَّامٍ إِلَّا رَمْزًا ۗ وَاذْكُر رَّبَّكَ كَثِيرًا وَسَبِّحْ بِالْعَشِيِّ وَالْإِبْكَارِ
(Zakariyya) so pe: “Oluwa mi, fun mi ni ami kan.” (Molaika) so pe: "Ami re ni pe iwo ko nii le ba eniyan soro fun ojo meta ayafi titoka (si nnkan). Ranti Oluwa re lopolopo. Ki o si safomo (fun Un) ni asale ati ni owuro kutu
42وَإِذْ قَالَتِ الْمَلَائِكَةُ يَا مَرْيَمُ إِنَّ اللَّهَ اصْطَفَاكِ وَطَهَّرَكِ وَاصْطَفَاكِ عَلَىٰ نِسَاءِ الْعَالَمِينَ
(E ranti) nigba ti awon molaika so pe: “Moryam, dajudaju Allahu sa o lesa. O fo o mo. O si sa o lesa lori awon obinrin aye (asiko tire)
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
40Ẹsẹ
Itumọ — Aal-Imran 40
Surah Aal-Imran Ẹsẹ 40 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Zakariyya) so pe: “Oluwa mi, bawo ni emi yoo se…Surah Ẹsẹ 40/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 38–42. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








