Aal-Imran · 60/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ فَلَا تَكُن مِّنَ الْمُمْتَرِينَ ۝٦٠
Alhaqqu mir Rabbika falaa takum minal mumtareen
📖 Ni Yorùbá
Ododo ni lati odo Oluwa re. Nitori naa, ma se wa ninu awon oniyemeji

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 58-62 — Surah Aal-Imran

58ذَٰلِكَ نَتْلُوهُ عَلَيْكَ مِنَ الْآيَاتِ وَالذِّكْرِ الْحَكِيمِ
Iyen ni A n ke fun o ninu awon ayah ati iranti ti o kun fun ogbon ijinle (iyen, al-Ƙur’an)
59إِنَّ مَثَلَ عِيسَىٰ عِندَ اللَّهِ كَمَثَلِ آدَمَ ۖ خَلَقَهُ مِن تُرَابٍ ثُمَّ قَالَ لَهُ كُن فَيَكُونُ
Dajudaju iru ‘Isa lodo Allahu da bi iru Adam; (Allahu) da a lati ara erupe. Leyin naa, O so pe: “Je bee.” O si je bee. eru Olohun ati Anabi Olohun. Amo siso ti awon kristieni so Anabi ‘Isa (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) di oluwa won olugbala won
60الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ فَلَا تَكُن مِّنَ الْمُمْتَرِينَ
Ododo ni lati odo Oluwa re. Nitori naa, ma se wa ninu awon oniyemeji
61فَمَنْ حَاجَّكَ فِيهِ مِن بَعْدِ مَا جَاءَكَ مِنَ الْعِلْمِ فَقُلْ تَعَالَوْا نَدْعُ أَبْنَاءَنَا وَأَبْنَاءَكُمْ وَنِسَاءَنَا وَنِسَاءَكُمْ وَأَنفُسَنَا وَأَنفُسَكُمْ ثُمَّ نَبْتَهِلْ فَنَجْعَل لَّعْنَتَ اللَّهِ عَلَى الْكَاذِبِينَ
Nitori naa, enikeni ti o ba ja o niyan nipa re leyin ohun ti o de ba o ninu imo, ki o so pe: “E wa! Ki a pe awon omokunrin wa ati awon omokunrin yin ati awon obinrin wa ati awon obinrin yin ati awa ati eyin naa. Leyin naa, ki a se adua taratara, ki a si toro egun Allahu le awon opuro lori.”
62إِنَّ هَٰذَا لَهُوَ الْقَصَصُ الْحَقُّ ۚ وَمَا مِنْ إِلَٰهٍ إِلَّا اللَّهُ ۚ وَإِنَّ اللَّهَ لَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Dajudaju eyi, ohun ni itan ododo. Ati pe ko si olohun kan ti ijosin to si afi Allahu. Dajudaju Allahu, Oun ni Alagbara, Ologbon
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
60Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 60

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 60 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ododo ni lati odo Oluwa re. Nitori naa, ma se…

Surah Ẹsẹ 60/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 58–62. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers