Aal-Imran · 59/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
إِنَّ مَثَلَ عِيسَىٰ عِندَ اللَّهِ كَمَثَلِ آدَمَ ۖ خَلَقَهُ مِن تُرَابٍ ثُمَّ قَالَ لَهُ كُن فَيَكُونُ ۝٥٩
Inna masala `Eesaa `indal laahi kamasali Aadama khalaqahoo min turaabin summa qaala lahoo kun fayakoon
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju iru ‘Isa lodo Allahu da bi iru Adam; (Allahu) da a lati ara erupe. Leyin naa, O so pe: “Je bee.” O si je bee. eru Olohun ati Anabi Olohun. Amo siso ti awon kristieni so Anabi ‘Isa (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) di oluwa won olugbala won

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 57-61 — Surah Aal-Imran

57وَأَمَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ فَيُوَفِّيهِمْ أُجُورَهُمْ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ الظَّالِمِينَ
Ni ti awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, (Allahu) maa fun won ni esan won ni kikun. Allahu ko si feran awon alabosi
58ذَٰلِكَ نَتْلُوهُ عَلَيْكَ مِنَ الْآيَاتِ وَالذِّكْرِ الْحَكِيمِ
Iyen ni A n ke fun o ninu awon ayah ati iranti ti o kun fun ogbon ijinle (iyen, al-Ƙur’an)
59إِنَّ مَثَلَ عِيسَىٰ عِندَ اللَّهِ كَمَثَلِ آدَمَ ۖ خَلَقَهُ مِن تُرَابٍ ثُمَّ قَالَ لَهُ كُن فَيَكُونُ
Dajudaju iru ‘Isa lodo Allahu da bi iru Adam; (Allahu) da a lati ara erupe. Leyin naa, O so pe: “Je bee.” O si je bee. eru Olohun ati Anabi Olohun. Amo siso ti awon kristieni so Anabi ‘Isa (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) di oluwa won olugbala won
60الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ فَلَا تَكُن مِّنَ الْمُمْتَرِينَ
Ododo ni lati odo Oluwa re. Nitori naa, ma se wa ninu awon oniyemeji
61فَمَنْ حَاجَّكَ فِيهِ مِن بَعْدِ مَا جَاءَكَ مِنَ الْعِلْمِ فَقُلْ تَعَالَوْا نَدْعُ أَبْنَاءَنَا وَأَبْنَاءَكُمْ وَنِسَاءَنَا وَنِسَاءَكُمْ وَأَنفُسَنَا وَأَنفُسَكُمْ ثُمَّ نَبْتَهِلْ فَنَجْعَل لَّعْنَتَ اللَّهِ عَلَى الْكَاذِبِينَ
Nitori naa, enikeni ti o ba ja o niyan nipa re leyin ohun ti o de ba o ninu imo, ki o so pe: “E wa! Ki a pe awon omokunrin wa ati awon omokunrin yin ati awon obinrin wa ati awon obinrin yin ati awa ati eyin naa. Leyin naa, ki a se adua taratara, ki a si toro egun Allahu le awon opuro lori.”
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
59Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 59

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 59 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju iru ‘Isa lodo Allahu da bi iru Adam; (Allahu)…

Surah Ẹsẹ 59/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 57–61. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers