Aal-Imran · 65/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تُحَاجُّونَ فِي إِبْرَاهِيمَ وَمَا أُنزِلَتِ التَّوْرَاةُ وَالْإِنجِيلُ إِلَّا مِن بَعْدِهِ ۚ أَفَلَا تَعْقِلُونَ ۝٦٥
Yaaa Ahlal Kitaabi limaa tuhaaajjoona feee Ibraaheema wa maaa unzilatit Tawraatu wal Injeelu illaa mim ba`dih; afala ta`qiloon
📖 Ni Yorùbá
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi jiyan nipa (Anabi) ’Ibrohim? A ko si so at-Taorah ati al-’Injil kale bi ko se leyin re, se e ko se laakaye ni
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 63-67 — Aal-Imran

63فَإِن تَوَلَّوْا فَإِنَّ اللَّهَ عَلِيمٌ بِالْمُفْسِدِينَ
Ti won ba si peyin da (nibi ododo naa), dajudaju Allahu ni Onimo nipa awon obileje
64قُلْ يَا أَهْلَ الْكِتَابِ تَعَالَوْا إِلَىٰ كَلِمَةٍ سَوَاءٍ بَيْنَنَا وَبَيْنَكُمْ أَلَّا نَعْبُدَ إِلَّا اللَّهَ وَلَا نُشْرِكَ بِهِ شَيْئًا وَلَا يَتَّخِذَ بَعْضُنَا بَعْضًا أَرْبَابًا مِّن دُونِ اللَّهِ ۚ فَإِن تَوَلَّوْا فَقُولُوا اشْهَدُوا بِأَنَّا مُسْلِمُونَ
So pe: “Eyin ahlu-l-kitab, e wa sibi oro kan t’o dogba laaarin awa ati eyin, pe a o nii josin fun eni kan afi Allahu. A o si nii fi kini kan wa akegbe fun Un. Ati pe apa kan wa ko nii so apa kan di oluwa leyin Allahu.” Ti won ba si gbunri, e so pe: “E jerii pe dajudaju musulumi ni awa.”
65يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تُحَاجُّونَ فِي إِبْرَاهِيمَ وَمَا أُنزِلَتِ التَّوْرَاةُ وَالْإِنجِيلُ إِلَّا مِن بَعْدِهِ ۚ أَفَلَا تَعْقِلُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi jiyan nipa (Anabi) ’Ibrohim? A ko si so at-Taorah ati al-’Injil kale bi ko se leyin re, se e ko se laakaye ni
66هَا أَنتُمْ هَٰؤُلَاءِ حَاجَجْتُمْ فِيمَا لَكُم بِهِ عِلْمٌ فَلِمَ تُحَاجُّونَ فِيمَا لَيْسَ لَكُم بِهِ عِلْمٌ ۚ وَاللَّهُ يَعْلَمُ وَأَنتُمْ لَا تَعْلَمُونَ
Eyin ni iwonyi ti e n jiyan nipa ohun ti e nimo nipa re! Ki ni o tun n mu yin jiyan nipa ohun ti e o nimo nipa re? Allahu nimo. Eyin ko si nimo
67مَا كَانَ إِبْرَاهِيمُ يَهُودِيًّا وَلَا نَصْرَانِيًّا وَلَٰكِن كَانَ حَنِيفًا مُّسْلِمًا وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
(Anabi) ’Ibrohim ki i se yehudi, ki i se kristieni, sugbon o je oluduro-deede, musulumi. Ko si si ninu awon osebo
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
65Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 65

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 65 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi jiyan nipa…

Surah Ẹsẹ 65/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 63–67. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers