Sad · 60/88
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Sad
قَالُوا بَلْ أَنتُمْ لَا مَرْحَبًا بِكُمْ ۖ أَنتُمْ قَدَّمْتُمُوهُ لَنَا ۖ فَبِئْسَ الْقَرَارُ ۝٦٠
Qaaloo bal antum laa marhabam bikum; antum qaddamtumoohu lanaa fabi`sal qaraar
📖 Ni Yorùbá
(Awon omoleyin ninu Ina) maa wi pe: "Rara, eyin naa ko si maawole-maarora fun yin. Eyin l’e pe wa sibi eyi (t’o bi Ina)." O si buru ni ibugbe

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 58-62 — Surah Sad

58وَآخَرُ مِن شَكْلِهِ أَزْوَاجٌ
Orisirisi (iya) miiran bi iru re (tun wa fun won)
59هَٰذَا فَوْجٌ مُّقْتَحِمٌ مَّعَكُمْ ۖ لَا مَرْحَبًا بِهِمْ ۚ إِنَّهُمْ صَالُو النَّارِ
Eyi ni ijo kan t’o maa wo inu Ina pelu yin. (Awon asiwaju ninu Ina si maa wi pe:) "Ko si maawole-maarora fun won." Dajudaju won yoo wo inu Ina ni
60قَالُوا بَلْ أَنتُمْ لَا مَرْحَبًا بِكُمْ ۖ أَنتُمْ قَدَّمْتُمُوهُ لَنَا ۖ فَبِئْسَ الْقَرَارُ
(Awon omoleyin ninu Ina) maa wi pe: "Rara, eyin naa ko si maawole-maarora fun yin. Eyin l’e pe wa sibi eyi (t’o bi Ina)." O si buru ni ibugbe
61قَالُوا رَبَّنَا مَن قَدَّمَ لَنَا هَٰذَا فَزِدْهُ عَذَابًا ضِعْفًا فِي النَّارِ
Won (tun) wi pe: "Oluwa wa, eni ti o pe wa (sibi iya) yii, se alekun adipele iya fun un ninu Ina
62وَقَالُوا مَا لَنَا لَا نَرَىٰ رِجَالًا كُنَّا نَعُدُّهُم مِّنَ الْأَشْرَارِ
Won tun wi pe: "Ki lo sele si wa ti a o ri awon okunrin kan, awon ti a n ka mo awon eni buruku
SadAtokọ Kurani
88Ẹsẹ
MeccanRevelation
60Ẹsẹ

Itumọ — Sad 60

Surah Sad Ẹsẹ 60 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Awon omoleyin ninu Ina) maa wi pe: "Rara, eyin naa…

Surah Ẹsẹ 60/88 — Surah Sad ص (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Sad Gbọ, Surah Sad Itumọ, Surah Sad mp3, Surah Sad pdf. Ẹsẹ 58–62. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers